Jump to content

Aisha Muhammed-Oyebode

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Aisha Muhammed-Oyebode
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kejìlá 1963 (1963-12-24) (ọmọ ọdún 61)
Iléẹ̀kọ́ gíga
Olólùfẹ́Gbenga Oyebode
Àwọn ọmọ3

Aisha Muhammed-Oyebode (tí wọ́n bí ní 24 December 1963) jẹ́ agbẹjọ́rò, oníṣòwò, òǹkọ̀wé àti ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[1] Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, òun ni adarí àgbà fún Asset Management Group Limited àti Murtala Muhammed Foundation.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Lekoil Appoints Aisha Muhammed-Oyebode Board Chairman – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2023-02-10. 
  2. "Lekoil names Aisha Muhammed-Oyebode as board chairperson". www.premiumtimesng.com. January 20, 2021. Retrieved 2023-02-10.