Jump to content

Ajá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ajá
Domestic dog
Temporal range: 0.015–0 Ma
Pleistocene – Recent
Dogs
Ipò ìdasí
Ọ̀sìn
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Ìdílé:
Ìbátan:
Irú:
Irú-ọmọ:
C. l. familiaris
Ìfúnlórúkọ mẹ́ta
Canis lupus familiaris
Synonyms
  • Canis familiaris
  • Canis familiaris domesticus
hound ni oko

Ajá (Dog) Àjà je ẹranko pelu ẹsẹ mẹrin. Won sáré kiakia ati won le ran awon èniyàn lowo, awon èniyàn ti ko le ri, awa n pe won "èniyàn afójú".

Awon ajá le sáré pèlú iyara ti àádóta kilomita ni wakati ọkan (50km/w). Sugbon o ma yipada fun ajá yato nitori awa ni orisirisi aja.[1]

Awon ajá je dabi kọlọkọlọ, akátá, ati awon ikokò. Awon ajá je lokiki, won ti ran awon ọdẹ lowo lati dẹ àwọn ẹranko.[2]

àwọn ajá ibọn

Àwọn miiran ajá ti awa ni je "hounds" tumo si ni èdè Yoruba je "oninunibini" awa n pe won yi nitori pé won n lo àwọn hounds lati se inunibini si àwọn ẹranko miiran dabi ehoro ati agbonrin. [3] Ati won n lo àwọn ajá ibọn lati wa ati mo ipo ti àwọn ẹranko ti o le parada ati pamó ara won dada. Àwọn ajá yii, ajá ibon si wa àwọn eye aparo ati àwọn eranko kékeré.[3]

Ajá (Kameroon)