Ajibade Gbadegesin Ogunoye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Olowo Ajibade Gbadegesin Ogunoye
Ogunoye ni àsìkò ọdún Ìgògò ní ìlú Ọ̀wọ̀
Reign 2019 – present
Predecessor Folagbade Olateru Olagbegi III
Spouse Olori Olanike Ogunoye
Father Adekola Ogunoye II
Mother Olori Adenike Yeyesa Ogunoye
Born 6 Oṣù Keje 1966 (1966-07-06) (ọmọ ọdún 57)
Owo, Ondo State, Nigeria

Ajibade Gbadegesin Ogunoye je agbejoro, osise Ipinle Ondo tele. O si je oba Ilu Owo.[1]

Ise re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

O je oba leyin ti oba ana, Folagbade Olateru Olagbegi III papo'da. Kí ó tó di Ọba, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ìjọba Ìpínlẹ̀ Òndó gẹ́gẹ́ bí Adarí ìṣàkóso ìṣúná lábẹ́ ìjọba Ìpínlẹ̀ Ondo.[2][3]

Awon itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Gbadegesin becomes new Olowo Of Owo - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2019-07-13. Retrieved 2022-01-29. 
  2. "Olowo-elect : I’m not surprised Prince Ogunoye emerged almost unopposed – Ikubese". Vanguard News. 2019-08-10. Retrieved 2022-01-29. 
  3. "BREAKING: Ogunoye Ajibade Gbadegesin emerges as Olowo elect -". TVC News. 2019-07-12. Retrieved 2022-01-29. 

'