Ìlú Ọ̀wọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ilu Owo wa ni ipinle Ondo, guusu iwọ-oorun Naijiria, ni iha guusu ti awọn Oke ile Yoruba (igbega 1,130 ẹsẹ ) ati ni ikorita awọn ọna lati Akure, Kabba, Ilu Benin, ati Siluko. Cocoa je ikan lara awon oun ogbin ti o wopo ni ilu owo.[1]

Owo je ikan lara awon ijoba ibile ni ipinle Ondo.[2] Oba Owo ni won n pe ni olowo ti Ilu Owo. Oba ti o wa lori ite lowolowo ni Ajibade Gbadegesin Ogunoye.[3]


Ìtàn ṣókí nípa Ọ̀wọ̀ láti ẹnu ọmọ bíbí Ìlú Ọ̀wọ̀.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Owo - Nigeria". Encyclopedia Britannica. 2009-01-09. Retrieved 2022-01-29. 
  2. Olugbamila, Omotayo Ben; Adeyinka, Samson Ajibola (2017-08-31). "Analysis of Socio-Economic Characteristics and Utilization of Healthcare Facilities in Owo Local Government Area of Ondo State, Nigeria". European Scientific Journal, ESJ 13 (23): 377–377. doi:10.19044/esj.2017.v13n23p377. ISSN 1857-7431. https://eujournal.org/index.php/esj/article/view/9818. Retrieved 2022-01-29. 
  3. "Gbadegesin becomes new Olowo Of Owo - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2019-07-13. Retrieved 2022-01-29.