Ajuma Ameh

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ajuma Ameh-Otache
Personal information
Ọjọ́ ìbí(1984-12-01)1 Oṣù Kejìlá 1984
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ọjọ́ aláìsí10 November 2018(2018-11-10) (ọmọ ọdún 33)
Playing positionMidfielder
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Pelican Stars
National team
Nigeria women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Ajuma Ameh jẹ ọkan lara agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 1, óṣu December ni ọdun 1984. Elere na ṣere fun pelician stars gẹgẹbi midfielder. Ajuma Ameh ku ni ọjọ kewa, óṣu December ni ọdun 2018 ni ọmọ ọdun mẹtalelọgbọn[1][2][3].

Àṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ameh kopa ninu olympic ni ọdun 2004 fun apapọ team awọn obinrin lori bọọlu gẹgẹbi àṣoju orilẹ ede naigiria[4][5].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-06-28. Retrieved 2022-05-30. 
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2021-05-12. Retrieved 2022-05-30. 
  3. https://fbref.com/en/players/e8954f23/Ajuma-Ameh
  4. https://www.olympiandatabase.com/index.php?id=250120&L=1
  5. https://flourishafrica.com/former-nigerian-player-ajuma-ameh-otache-pass-away-at-33/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]