Jump to content

Akasha (fiimu 2018)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
aKasha
Fáìlì:Akasha (2018 film).jpg
Film poster
AdaríHajooj Kuka
Olùgbékalẹ̀
• Hajooj Kuka
• Steven Markovitz
Òǹkọ̀wéHajooj Kuka
Àwọn òṣèré
• Ekram Marcus
• Kamal Ramadan
• Mohamed Chakado
Orin
Ìyàwòrán sinimá
• Giovanni P. Autran
• Hajooj Kuka
OlóòtúHajooj Kuka
Ilé-iṣẹ́ fíìmù
• Big World Cinema
• Refugee Club
• Komplizen Film
Déètì àgbéjáde
• Oṣù Kẹjọ 31, 2018 (2018-08-31) (Venice)
Àkókò78 minutes
Orílẹ̀-èdè
• Sudan
• South Africa
• Qatar
• Germany
ÈdèArabic

Akasha jẹ fiimu apanilerin ti ilu Sudan ti ọdun 2018 ti Hajooj Kuka kọ ti osi tun dari, oda lori ọmọ ogun Sudan kan ti o wa laarin ifẹ rẹ si ọrẹbinrin rẹ ati AK-47 rẹ. Kuka tẹlẹ dari orisirisi ere itan. Akasha jẹ fiimu itan-akọọlẹ akọkọ rẹ osi ṣe afihan ni Venice Film Festival ni Oṣu Kẹjọ Ọjọ kokan lelogbon, Ọdun 2018.

Adnan ti gba akoko kuro nibii iṣẹ rẹ bi ọmọ ogun rogbodiyan fun mimu waale ọkọ ofurufu onija MiG kan, ni bayi o jẹwọ ifẹ rẹ si AK-47 ti o lo fun ikolu naa, o so ibon na ni Nancy. Ọrẹbinrin rẹ Lina ko ni idunnu nipa ifẹ miiran to ni fun ibon yii, nitorinaa o fi siile. Ni arin wakati meerin lelogun, Alakoso rẹ gbiyanju lati ko gbogbo awọn aginju naa jọ, Adnan si ṣe akojọpọ awọn eto lati gba Nancy pada, eyiti o fi silẹ lairotẹlẹ ni ile Lina. Ni gba ti o n lo aginju miiran, Absi ran lowo, ti o gbagbọ ninu kafi idaroro paari ogun.[1][2]

• Kamal Ramadan bi Adnan
• Ekram Marcus bi Lina
• Mohamed Chakado bi Absi
• Abdallah Alnur bi Blues

Kuka pade meji ninu awọn oṣere olori, Mohamed Chakado ati Kamal Ramadan, lakoko ti o nkọ ere ni ile-iṣẹ ọdọ ti agbegbe kan, o pinnu lati gbe wọn sinu fiimu naa.[3]O lo Ekram Marcus bi Lina ṣiṣẹ nitori pe o ni ihuwasi na: yiyan lati lepa eto-ẹkọ ju ki o ṣe igbeyawo.[4]

Fiimu naa ṣe afihan ni ayeye Venice Film Festival ni osu keejo ojo 3kokan lelogbon,odun 2018, o si ṣe afihan ni Toronto International Film Festival . Meji ninu awọn oṣere, Kamal Ramadan ati Mohamed Chakado, ko le lọ si awọn ayẹyẹ nitori ilu Uganda kọ lati gba wọn laaye lakoko ti o n duro de iwe ipo asasala wọn. Fiimu naa tun ṣe afihan ni ayeye Africa in Motion ni Edinburgh .[5]

aKasha gba adalu agbeyewo. Alvise Mainardi ti Non Solo Cinema kowe pe botilẹjẹpe isuna kekere han kedere, o ṣoro lati ma fẹran rẹ.[6] Martina Barone ti Cinematographe ro pe fifa tikotiko awọn iṣere fa didara fiimu naa silẹ, iṣafihan akọkọ yii fihan pe oludari ni talenti fun ṣiṣe fiimu.[7]

1. Shiri, Keith (11 October 2018). "Don't miss! Four films for Thursday 11 October". British Film Institute. Archived from the original on 31 August 2019. Retrieved 31 August 2019.
2. Agarwal, Manish (8 October 2018). "Three to see at LFF if you like... African films". British Film Institute. Retrieved 31 August 2019.
3. Vourlias, Christopher (29 August 2018). "Venice: Two Refugee Sudanese Actors Unable to Attend Film Premiere". Variety. Retrieved 1 October 2018.
4. Àdàkọ:Cite AV media
5. Stephen, Phyllis (25 September 2018). "Africa in Motion Film Festival 26 October to 4 November 2018". The Edinburgh Reporter. Retrieved 1 October 2018.
6. Mainardi, Alvise (31 August 2018). ""aKasha" di Hajooj Kuka". NonSoloCinema (in Italian). Retrieved 1 October 2018. Il budget rimane risicato, e talvolta nell’opera ben si nota questa caratteristica, ma il lavoro che riesce a imbastire pur con tutti i suoi difetti è difficile da disprezzare, vuoi per lo sguardo ironico con cui affronta un tema complesso, vuoi per l’assoluta mancanza di retorica.
7. Barone, Martina (2 September 2018). "Venezia 75 – aKasha (The Roundup): recensione". Cinematographe (in Italian). FilmIsNow. Retrieved 1 October 2018. Un film decisamente semplice in cui purtroppo gli attori non contribuiscono ad alzare il livello della prestazione generale dell’opera e anzi, a volte, sembrano addirittura abbassare ancora di più il livello qualitativo del tutto. Di certo un tentativo di cinema contemporaneo che mostra la conoscenza delle dinamiche della narrazione, non sapendole però utilizzare al loro meglio, creando un film ingenuo, ma che presenta le abilità di questo aspirante regista.