Akin Euba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Akin Euba (born Olatunji Akin Euba, Lagos, Nigeria, April 28, 1935)

Ise Akin Euba ni onkowe ye wo ninu ise re yii. Loooto, ilana awon nGeesi ni Akin Euba fi n korin sugbon asa awon Yoruba ni o gbe ise re ka. Onkowe yii soro nipa iwadii ti Akin Euba se lori ilu. Onkowe yii ko saipin orin si isori. Gbogbo eni ti o ba ni nnkan se pelu tilutifon (music) ni iwe yii yoo wulo fun.

  • Joshua Uzoigwe (1992), Akin Euba: An Introduction to the Life and Music of a Nigerian Composer (Bayreuth African Studies Series 25). Bayreuth: Eckhard Beitinger. ISBN 3-927510-16-5; ISSN: 0178-0034. Oju-iwe = 109.