Akinsola Olusegun Faluyi
Akinsola Olusegun Faluyi | |
---|---|
President of the Nigerian Society of Engineers (NSE) | |
In office 1985–1986 | |
President of the Council for the Regulation of Engineering (COREN) | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kọkànlá 1934 |
Akinsola Olusegun Faluyi (ẹni tí wọ́n bí ní ọjọ́ 13 oṣù kọkànlá ọdún 1934) jẹ́ òṣìṣẹ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ àti ààrẹ́ COREN tẹ́lẹ̀ rí ,ikọ̀ ìmọ̀ ẹ̀rọ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1]
Ìgbésí ayé àti isẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orúkọ mìíràn tí ó ń jẹ́ ni "Olusegun" tí ògbufọ̀ rẹ jẹ́ "God is Victorious" ní èdè Gẹ̀ẹ́sì[2] ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ńdírì Ibadan Boys High School, ìpínlẹ̀Oyo, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní bi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí (WASC) tí ó sì tẹ̀síwájú lọ sí fáfitì ní bi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí fáfitì àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ (B.Eng) in Mechanical engineering (1953-1985).ó dara pọ̀ mọ́ òṣìṣẹ́ ilé ìwòsàn ilé ìwé fáfitì ìlú Ìbàdàn gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ ẹ̀rọ ní ọdún 1960.[3] Ó kúrò ní ilé ìwòsàn lẹ́yìn ọdún méjì gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ ẹ̀rọ ní ilé ìwòsàn, ó dara pọ̀ mọ́ ilé ìwòsàn ìlú Èkó ní ọdún 1962,gẹ́gẹ́ bíi ọ̀gá àgbà onímọ̀ ẹ̀rọ. Ní ọdún 1975 ó ẹ̀yìn tì ní ilé ìwòsàn fáfitì Èkó láti dara pọ̀ mọ́ Edisson Group and partners.[4] Ọ́ di ààrẹ́ àpapọ̀ àwọn onímọọ̀ ẹ̀rọ ní 2985 ó sì sìn wọ́n fún ọdún kan, tí sáà náà parí lẹ́yìn ọdún kan, ṣáá tí ó parí ní ọdún 1986.[5] Ó padà di Ààrẹ COREN.[6] Ó sì sì wọ́n gẹ́gẹ́ bíi ààrẹ́ Nigerian Academy of Engineering.[7]
Àwọn ẹgbẹ́ tó darapọ̀ mọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Fellow, Nigerian Society of Engineers (NSE)
- Fellow, Nigerian Academy of Engineering
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Faluyi, A. O. (1993). The Making of an Engineer. https://books.google.com/books?id=OvcaHQAACAAJ.
- ↑ "Olusegun". Nigerian Name.
- ↑ RapidxHTML. "The Nigeria Academy of Engineering :: promoting excellence in technology and engineering training and practice to ensure the technological growth and economic development of Nigeria". Archived from the original on 2016-12-16. Retrieved 2024-02-08.
- ↑ "BiafraNigeriaWorld: The Authority on BiafraNigeria". Archived from the original on 2013-04-03. Retrieved 2024-02-08.
- ↑ "NSE Membership Portal". Archived from the original on 2014-12-05. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Reference at allafrica.com".
- ↑ "BNW News: BiafraNigeriaWorld News: Biafra Nigeria World is the Authority on BiafraNigeria, Biafra NigeriaWorld". Archived from the original on 2021-02-11. Retrieved 2024-02-08.