Jump to content

Akite Agnes

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Akite Agnes
Akite Agnes in March 2015
Orúkọ àbísọAkite Agnes Opio
Ìbí(1983-03-19)19 Oṣù Kẹta 1983
Kampala, Uganda
MediumStand-up, Television
Ajẹ́ọmọorílẹ̀-èdèUgandan
Genresobservational comedy, self-deprecation
Subject(s)Every day life, relationships
SpouseBrian Makalama

Akite Agnes (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹta ọdún 1983) jẹ́ òṣèré àti aláwàdà[1][2] lórílẹ̀-èdè Uganda.[3]

Ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Akite gboyè nínú tourism láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Makere University.[4]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2014, Akite bẹ̀rẹ̀ àwàdà ṣíṣe pẹ̀lú ẹgbẹ́ The Punchliners..[5][6] Ní ọdún 2016, ó kópa nínú eré Girl From Mparo gẹ́gẹ́ bí Mama Brian[7]. Ní oṣù kẹfà ọdún 2018, ó kópa níbi ayẹyẹ Kampala Comedy Festival èyí tí Okello Okello gbé kalẹ̀.[8][9][10][11] Láàrin oṣù kẹjọ àti oṣù kọkànlá, ẹgbẹ́ UG Pineapple Comedy Tour tí ó wà gbé lọ oríṣiríṣi ìlú bíi Mbale, Gulu, Fort Portal, Jinja àti Mbarara[12][13]. Ó ṣe àwàdà níbi ètò apá kẹrin ti African Laughs ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹwàá ọdún 2018.[14] Ní oṣù kẹta ọdún 2019, ó gbé ètò Arise Woman! Comedy Jam kalẹ̀.[15][16] Ní oṣù náà ni ó tún farahàn ni Kigali fún ayẹyẹ Seka Fest.[17] Ní osù keje ọdún 2019, ó wà lára àwọn tó se àwàdà níbi ayẹyẹ Laugh Festival ní Nairobi.[18][19]

Ìgbésí ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Akite jẹ́ ọmọ karùn-ún nínú ọmọ mẹ́jọ tí àwọn òbí rẹ bí. Ó ti bí ọmọ méjì.[20]

Àsàyàn eré rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó
2009–2012 The Hostel Arach
2016 Girl from Mparo Mama Brian
2018–present Mizigo Express Sam's girlfriend

Àwọn Ìtọ́kàsi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Nantaba, Agnes (October 19, 2018). "Agnes Akite aka Arach on Funny Ugandans". Uganda News Archive. Archived from the original on December 8, 2020. 
 2. Daheley, Tina. "Comedy That Changes Minds". BBC World Service - The Cultural Frontline. Retrieved 3 July 2019. 
 3. "Comedienne Agnes Akite’s complicated path to stardom". Daily Monitor (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-06-01. 
 4. "Comedienne Agnes Akite’s complicated path to stardom". Daily Monitor (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-06-01. 
 5. Àdàkọ:Cite podcast
 6. Katongole, George (16 February 2019). "Comedienne Agnes Akite’s complicated path to stardom". Daily Monitor. 
 7. "Girl From Mparo". Uganda Broadcasting Corporation. Archived from the original on 21 November 2018. Retrieved 10 October 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 8. Atungisa, Don (2 July 2018). "PHOTOS: How it Went Down at the Inaugural Kampala Comedy Festival — MTN Pulse". pulse.mtn.co.ug. Retrieved 2018-10-03. 
 9. Nakassanje, Winnie (5 July 2018). "The First Ever Kampala Comedy Festival Reveals New Internationals". The Kampala Sun. Archived from the original on 21 November 2018. Retrieved 10 October 2018. 
 10. Ampurire, Paul (20 July 2018). "Comedienne Agned Arach Impresses Revellers on Comedy Store". Soft Power News. Retrieved 10 October 2018. 
 11. Zamboki, Lincoln (2018-08-06). "Comedienne Agnes AKite heaped with praise by fans after her clip went viral" (in en-US). MBU. https://mbu.ug/2018/08/06/comedienne-agnes-akite-heaped-with-praise-by-fans-after-her-clip-went-viral. 
 12. Sources:
 13. Ampurire, Paul (25 September 2018). "PICTORIAL: MC Mariachi Wows Mbarara During Comedy Store's Tour". SoftPower News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 26 September 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 14. Sources:
 15. Kulanyi, Rachael (11 March 2019). "Female comedians celebrate Women’s day in a comedy show dubbed ‘Arise Woman Comedy Jam". Matooke Republic. Retrieved 12 March 2019. 
 16. Emuk, Benjamen (9 March 2019). "Ugandan Female Comics Dedicate ‘Arise Woman Comedy Jam’ Show To Charity". Chimp Reports. Archived from the original on 2 April 2019. Retrieved 12 March 2019. 
 17. Batte, Edgar. R (1 April 2019). "Ugandan comedians shine at Kigali’s Seka fest". Sqoop. Retrieved 2 April 2019. 
 18. Sources:
 19. "Comedy show fight against xenophobia". News24 (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-18. Retrieved 2019-12-26. 
 20. Baike, Prisca. "Comedian Agnes Akite has Bone to Pick with Minister Lokodo". The Observer. Archived from the original on November 20, 2018. Retrieved October 19, 2018.