Akudo Oguaghamba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Akudo Oguaghamba
Ọjọ́ìbíAkudo Oguaghamba
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ẹ̀kọ́University of Nigeria Nsukka
Iṣẹ́A jà fẹ́tọ́ ọmọnìyàn àti Olùkọ́

Akudo Oguaghamba ni ó jẹ́ a jà fẹ́tọ́ ọmọnìyàn, olùkọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti kọ ìwé ìwádí nípa ẹ̀tọ́ àwọn LGBTQ.[1][2] Òun ni olùdásílẹ̀ àjọ Women's Health and Equal Rights (WHER)[3][4] ó sì tún jẹ́ ọ̀kan kan ṣoṣo lára àwọn olùdásílẹ̀ PAN-AFRICAN ILGA (International Lesbian, Gay, Bisexual, Trans and Intersex Association) ati EQUITAS – International Centre for Human Rights[5] [6][7] Oguaghamba jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ jáde ilé-ẹ̀kọ́ University of Nigeria, Nsuuka[8]

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Pamela Adie". 9jafeminista (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-16. 
  2. "AKUDO OGUAGHAMBA". Equitas (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-16. 
  3. "Nigerian site invites reports of human rights abuses". NoStringsNG – Voice of LGBTQ+ Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-04. Retrieved 2021-06-16. 
  4. Johnson, Ruby; Sanjuan, Ledys (November 16, 2017). "Stronger Together: An Activist-Funder Dialogue on Resourcing Young Feminist Organization". GrantCraft. Retrieved July 20, 2021. 
  5. "Empowering Sexual Minority Women in Nigeria". Equitas (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-05-16. Retrieved 2021-06-16. 
  6. "Press Release: Pan Africa ILGA Hosts a Regional Conference In Kenya 2014". ILGA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-04-07. Archived from the original on 2021-06-24. Retrieved 2021-06-16. 
  7. "Why Lesbian and Bisexual Women Should Be Visible On LGBT Rights Advocacy In Nigeria - Akudo Oguaghamba". Where Love is a Crime (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-05-15. Archived from the original on 2021-06-24. Retrieved 2021-06-16. 
  8. admin. "2016-2017-POSTGRADUATE-ADMISSION-TO-VICE-CHANCELLOR" (PDF). UNN.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)