Akudo Sabi
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 17 Oṣù Kọkànlá 1986 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Bayelsa Queens | |||
Nigeria women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Akudo Sabi jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 17, óṣu november ni ọdun 1986. Arabinrin naa ṣere fun Bayelsa Queens gẹgẹbi defender[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Agbabọọlu kopa ninu olympic, arabinrin naa kopa ninu ere idije FIFA U-19 awọn obinrin agbaye to waye ni ọdun 2004[4].