Akwaeke Emezi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

[1]

Akwaeke Emezi
Akwaeke Emezi
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹfà 6, 1987 (1987-06-06) (ọmọ ọdún 36)
Umuahia, Nigeria
Ẹ̀kọ́New York University (MPA)
Iṣẹ́Writer
Gbajúmọ̀ fúnFreshwater
Pet
The Death of Vivek Oji
Websiteakwaeke.com

Akwaeke Emezi jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó wá láti ẹ̀ya lgbo. Ó jẹ́ òǹkọ̀wé Tamil àti olórin orí ẹ̀rọ fídíò, ẹni tí wọ́n mọ̀ dára jùlọ fún ti debut novel Freshwater ti ọdún 2018.[2]

Ìgbésí ayé e rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bàbá tí ó bí Emezi jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, nígbàtí ìyá rẹ wá láti Tamil ní orílẹ̀-èdè Indian. Ìlú Aba ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Emezi dàgbà sí.[3] Emezi àti arábìnrin rẹ̀, Yagazie[4] ma ńlo ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ láti sá fún àwọn ǹkan rúdurùdu tí ó ma ń ṣẹlẹ̀ ní ìgbà èwe wọn.[5] Emezi ti bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ àwọn ìtàn kúkúrú láti ìgbà tí ó ti wà ní ọmọ ọdún márún ún.[6] Ó gba oyè ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ lóríi MPA láti ilé-èkó gíga Yunifásítì ti ìlú New York.[7]

Emezi má n lo àwọn ọ̀rọ̀ oyè bíi wọ́n/wọ́n/tiwọn. Wọ́n ní ìrírí ìsọdipúpọ̀, nípa báyìí ni wọ́n ṣe ro ara wọn sí́ ọgbanje.[8][9]

Omi tútù[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Omi tútù sọ ìtàn nípa ìtàn-àkọọ́lẹ̀ nípa Ada, ẹni tí ó jẹ́ ogbanje. Emezi ṣàwárí àwọn ogún èyà Ìgbò ti ó jẹ mọ́ ti ẹ̀mí, ìwà àti ìṣe, lẹ́gbẹ́ẹ̀gbẹ́ pẹ̀lú ti apá ìwọ̀òrùn láti pé kí àwọn olùgbọ wọn ronú jinlẹ̀ nípa àwọn nkan èmi yii.[10]

Gbígbàwọlé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Omi tútù yí gba iyì tí ó ṣe pàtàkì[11][12][13] àti wípé wón tí ṣe àkọọ́lẹ̀ rẹ sílẹ̀ láti ọjọ́ tí ó tipẹ́ fún òpòlopò àwọn ẹ̀bún olókìkí.[14][15][16] Emezi tún wà lára àwọn tí wọ́n bu ọlá fún nígbà íbọláfún ti National Book Foundation fún àwọn tí ọjọ́-orí wọn jẹ́ ọdún márún ùn sí ọdún márùndílógójì tí wọ́n ṣe ní ọdún 2018vtun jẹ idanimọ bi 2018.[17]

Ní ọdún 2019, wọ́n yan omi tútù fún Ẹ̀bùn àwọn Obìnrin fún ìtàn. Èyí jẹ́ ìgbà àkọkọ tí wọ́n máa yan oǹkọ̀wé transgender fún Ẹ̀bùn yìí. Ẹnití ó ṣe agbẹnusọ fún pínpín ẹ̀bùn àwọn obìnrin, Ọ̀jọ̀gbọ́n Kate Williams sọ wípé ìgbìmọ̀ tí ó ń darí ayẹyẹ yi kò mọ̀ pé Emezi kìí ṣe alákọméjì nígbàtí wọ́n yan ìwé yìí, ṣùgbọ́n ó sọ pé inú Emezi dún pé wọ́n yàn òun.[18] Alásọyé tí kìí ṣe alákọméjì, Vic Persons kọ ìwé pé yíyán yí mú àwọn ìbéèrè kòrọrùn wá. Bí ó ti sọ́ ọ́ nínú béèrè rẹ: "Ṣe òǹkọ̀wé tí kìí ṣe alákọméjì tí ó jẹ́ wípé ọkùnrin ni nígbàtí wọ́n bíi ni wọ́n ti ṣe àkọọ́lẹ̀ rẹ? Mo se iyèméjì púpọ̀".[19] Léhìn yíyàn, wọ́n kéde pé Ìgbìmọ̀ fún ẹ̀bùn àwọn obìnrin ń ṣiṣẹ́ lórí àwọn ìtọ́sọ́nà tuntun fún àwọn transgender, àwọn tí kìí ṣe alákọméjì àti àwọn ònkòwé tí wọ́n ń pè ní genderfluid.[20] Léhìn náà ni ẹ̀bùn fún àwọn obìnrin béèrè bóyá okùnrin ni Emezi ni tàbí obìnrin ni gégé bí òfin ti ṣe é lálàyé. Nígbàtí ó bá fi ikú ti Vivec Oji sílè fún àfikún, Emezi yàn láti jáwọ́ kúrò nínú pípe ìlànà tí transphobic ati ìyàsọ́tọ̀ pàtàkì sí àwọn trans tí ó jẹ́ obìnrin.[21]

Àwọn iṣẹ́ mìíràn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Pet, èyi tí ó jáde ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹsán án ọdún 2019, jẹ́ nípa ọ̀dọ́ transgender kan tí wọ́n ń pé ní Kan, ẹnití ń gbé ní àgbáyé níbití àwọn àgbàlagbà ti kọ̀ láti gbà wípé àwọn ohun ìbanilẹ́rù wa.[22]

Emezi fi ọwọ́ sí àdéhùn pẹ̀lú ilé ìtẹ̀wé Riverhead lóríi àwọn ìwé méjì. Èkínní ni Iku ti Vivet Oji, èyí tí ó jáde ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdún 2020 tí ó sì jẹ́ èyí tí ìwé ìròhìn New York Times tà jùlọ.[23] Èkejì jẹ́ ìwé àkọsílẹ̀ fún ìrántí tí àkọlé rẹ jẹ́ Dear Senthuran: A Black Spirit Memoir.[24]

Àwọn àmì ẹ̀yẹ àti yíyàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn èyí tí ó borí wọn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 2017 Astraea Lesbian Foundation for Justice Global Arts Fund Grant.[25][26]
  • 2017 Commonwealth Short Story Prize for Africa.[27]
  • 2019 Nommon Award for Freshwater.[28]
  • 2019 Otherwise Award for Freshwater.[29]
  • 2020 We Need Diverse Books water Honor Books, Teen Category.

Àwọn tí wọ́n yàn án sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Aspen Words Literary Prize.[30][31]
  • PEN/Hemingway award.[32][33]
  • Center for Fiction First Novel Prize.[34]
  • Carnegie Medal of Excellence.[35]
  • Ther Brooklyn Public Library litrary Prize.
  • 2019 Young Lions Fiction Award Finalists.[36]
  • 2019 National Book Award for Young People's Literature Finalist.[37]
  • 2019 Women;s Prize for Fiction|Women;s Prize for Fiction.]][38]
  • 2021 Dylan Thomas Prize[39].

Ìwé ìtàn-àkọọ́lẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Freshwater: A Novel, 2018.[40]
  • Pet, 2019.[41]
  • The Death of Vivec Oji, 2020.[42]
  • Dear Senthuran: A Black Spirit Memoir, 2021.[43]
  • Bitter, 2021.[44]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Nast, Condé (2018-01-11). "5 Families Who Are Changing The World as We Know It". Vogue. Retrieved 2021-09-15. 
  2. "In This Debut Novel, a College Student Hears Voices". The New York Times. 2018-02-26. Retrieved 2021-09-15. 
  3. "Books We Love: Inside The Bubble With Akwaeke Emezi - Death, Sex & Money". WNYC Studios. Archived from the original on 2021-09-15. Retrieved 2021-09-15. 
  4. Nast, Condé (2018-01-11). "5 Families Who Are Changing The World as We Know It". Vogue. Retrieved 2021-09-15. 
  5. "39: Akwaeke Emeziwriter and video artist". Mythos Magazine. 2018-02-19. Retrieved 2021-09-15. 
  6. Philyaw, Deesha (2018-02-21). "A Spirit Born into a Human Body: Talking with Akwaeke Emezi". The Rumpus.net. Retrieved 2021-09-15. 
  7. Emezi, Akwaeke (2017-09-15). "Freshwater". Grove Atlantic. Retrieved 2021-09-15. 
  8. Emezi, Akwaeke (2018-01-19). "Transition". The Cut. Retrieved 2021-09-15. 
  9. Whitehouse, Matthew (2018-12-24). "'Freshwater' author Akwaeke Emezi: "It's not superstition – it's true"". I-d. Retrieved 2021-09-15. 
  10. Emezi, Akwaeke (2018-02-17). "In 'Freshwater,' A College Student Learns To Live With Separate Selves". NPR.org. Retrieved 2021-09-15. 
  11. Nast, Condé (2018-02-26). "A Startling Début Novel Explores the Freedom of Being Multiple". The New Yorker. Retrieved 2021-09-15. 
  12. Adébáyò, Ayòbámi (2018-11-15). "Freshwater by Akwaeke Emezi review – a remarkable debut". the Guardian. Retrieved 2021-09-15. 
  13. "A dazzling, devastating novel: 'Freshwater' by Akwaeke Emezi". Los Angeles Times. 2018-02-16. Retrieved 2021-09-15. 
  14. "The Brooklyn Public Library Literary Prize". Brooklyn Public Library. 2017-03-20. Retrieved 2021-09-15. 
  15. Nast, Condé (2018-12-04). "The Best Books of 2018". The New Yorker. Retrieved 2021-09-15. 
  16. "NPR's Book Concierge". NPR.org. 2018-11-27. Retrieved 2021-09-15. 
  17. "National Book Foundation unveils this year's '5 Under 35' picks". Los Angeles Times. 2018-09-24. Retrieved 2021-09-15. 
  18. Cain, Sian (2019-03-04). "Non-binary trans author nominated for Women's prize for fiction". the Guardian. Retrieved 2021-09-15. 
  19. Parsons, Vic (2019-03-09). "Opinion: Be careful before celebrating the recognition of Akwaeke Emezi". The Independent. Retrieved 2021-09-15. 
  20. Wood, Heloise (2019-04-02). "Women's Prize to formulate new policy around gender criteria". The Bookseller. Retrieved 2021-09-15. 
  21. Flood, Alison (2020-10-05). "Akwaeke Emezi shuns Women's prize over request for details of sex as defined 'by law'". the Guardian. Retrieved 2021-09-15. 
  22. "Pet by Akwaeke Emezi: 9780593175446". PenguinRandomhouse.com. 2021-08-19. Retrieved 2021-09-15. 
  23. "The Death of Vivek Oji by Akwaeke Emezi: 9780525541622". PenguinRandomhouse.com. 2021-08-26. Retrieved 2021-09-15. 
  24. "Author Akwaeke Emezi Is Writing New Possibilities Into Being". Time. 2021-05-27. Retrieved 2021-09-15. 
  25. "Akwaeke Emezi Bio: Akwaeke Emezi is an Igbo/Tamil...". Global Arts Fund 2017. 2017-02-21. Retrieved 2021-09-16. 
  26. "Global Arts Fund Archives". Astraea Lesbian Foundation For Justice. 2015-09-30. Retrieved 2021-09-16. 
  27. "Who Is Like God". Granta. 2017-06-13. Retrieved 2021-09-16. 
  28. "Announcing the 2019 Nommo Award Winners". Tor.com. 2019-10-25. Retrieved 2021-09-16. 
  29. Lothian, Alexis (2020-04-11). "Akwaeke Emezi wins 2019 Otherwise Award! Honor List Announced « Otherwise Award". Otherwise Award. Retrieved 2021-09-16. 
  30. "AKWAEKE EMEZI". Aspen Words. 2021-06-07. Archived from the original on 2021-09-16. Retrieved 2021-09-16. 
  31. "7 Tips on Writing Fiction from Aspen Words Literary Prize Nominees". The Aspen Institute. 2019-01-10. Retrieved 2021-09-16. 
  32. "2019 PEN/Hemingway Award Finalists Announced". The Hemingway Society. Retrieved 2021-09-16. 
  33. "Akwaeke Emezi". Women's Prize for Fiction. 2019-03-03. Retrieved 2021-09-16. 
  34. "Page not found". The Center for Fiction. Archived from the original on 2021-09-16. Retrieved 2021-09-16. 
  35. "2021 Winners of the Andrew Carnegie Medals for Excellence in Fiction and Nonfiction". Reference & User Services Association (RUSA). 2020-10-18. Retrieved 2021-09-16. 
  36. "Young Lions Fiction Award Finalists – Locus Online". Locus Online – The Magazine of the Science Fiction and Fantasy Field. Retrieved 2021-09-16. 
  37. "The 2019 National Book Awards Finalists Announced". National Book Foundation. 2019-10-07. Retrieved 2021-09-16. 
  38. Cain, Sian (2019-03-04). "Non-binary trans author nominated for Women's prize for fiction". the Guardian. Retrieved 2021-09-16. 
  39. "Shortlist for Dylan Thomas Prize Is Revealed". Kirkus Reviews. Retrieved 2021-09-16. 
  40. "FRESHWATER". Akwaeke Emezi. 2021-08-16. Retrieved 2021-09-16. 
  41. "PET". Akwaeke Emezi. 2019-09-10. Retrieved 2021-09-16. 
  42. "THE DEATH OF VIVEK OJI". Akwaeke Emezi. 2020-08-04. Retrieved 2021-09-16. 
  43. "DEAR SENTHURAN". Akwaeke Emezi. 2021-08-16. Retrieved 2021-09-16. 
  44. "BITTER". Akwaeke Emezi. 2021-08-16. Retrieved 2021-09-16.