Jump to content

Aláàfin Eguguojo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Eguguojo (tí ó tún ń jẹ́ Egunoju) fìgbà kan jẹ́ Aláàfin ti ìlú Ọ̀yọ́ ní sẹ́ńtúrì kẹrìndínlógún.[1] Lásìkò ìjọba rẹ̀, wọ́n gbé olú ìlú náà kúrò ní Ọ̀yọ́ ilé lọ sí Ọ̀yọ́ Ìgbòho (ìyẹn Ọ̀yọ́ tuntun), lẹ́yìn tí wọ́n jagun pẹ̀lú Nupe tán, tí ó sì fa Ogun abélé. Kí wọ́n tó ṣe ìdásílẹ̀ Ọ̀yọ́ tuntun, bàbá bàbá rẹ̀ rin ìrìn-àjò ẹ̀mí, láti bọ́ lọ́wọ́ àwọn ẹ̀sọ́ ààfin.[2] Lẹ́yìn ìjọba rẹ̀, Aláàfin Ọ̀rọ̀mpọ̀tọ̀ ló jẹ oyè Aláàfin Ọ̀yọ́.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Mark R. Lipschutz; R. Kent Rasmussen (1989). Dictionary of African Historical Biography. University of California Press. ISBN 9780520066113. https://books.google.com/books?id=QYoPkk04Yp4C&q=Eguguojo+century+Yoruba&pg=PA188. 
  2. Akinbode, Ayomide; Ojeniyi, Ayo (2022-04-23). "Alaafin Oyo: Historic reign from.1210 to 2022". IROHIN ODUA. Retrieved 2024-06-15. 
  3. "Eguguojo Words". 5 Words Related to Eguguojo. Retrieved 2024-06-15.