Jump to content

Al-Iṣābah fī Tamyīz al-Ṣahābah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Al-Isabah fi tamyiz al Sahabah
Olùkọ̀wéIbn Hajar al-'Asqalani
Àkọlé àkọ́kọ́الإصابة في تمييز الصحابة
CountryEgypt
LanguageArabic (originally)
SubjectHadith,Muhammad,632 Arabian Peninsula,Sahabah Biography.
GenreSharh
PublisherDar al-kutub al-Ilmiyyah, Beirut
Publication date
1856-1873

Al-Iṣābah fī Tamyīz al-Ṣahābah (Lárúbáwá: الإصابة في تمييز الصحابة; A Morning in the Company of the Companions) jẹ́ ìwé àlàyé Sunni tí wọ́n kó ìwé hadith jọ tí Ibn Hajar Al Asqalani kọ. A gbóríyìn fún ìwé náà fún àkọsílẹ̀ àwọn akẹgbẹ́, àwọn ẹni tí wọ́n pàdé tí wọ́n sì gbé lákòókò tí Muḥammad wà láyé. Iṣẹ́ náà ní nínú ìtàn ìgbésí ayé Muḥammad, ìtàn ìgbésí ayé àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, ìtàn ìgbésí ayé àwọn ìyàwó rẹ̀, àti ìtàn ìgbésí ayé àwọn tābi, ìran àwọn onígbàgbọ́ tí wọ́n pàdé tí wọ́n sì kẹ́kọ̀ọ́ lábẹ́ Ṣàhābah. [1][2] Lárúbáwá ni a fi kọ ìwé náà.[2]

  1. Team, IslamiEducation (2009-11-20). "al-Isabah fi tamyiz-is-sahabah - Ibn Hajr Asqalani". IslamiEducation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-08-06. 
  2. 2.0 2.1 Ibn Ḥajar al-ʻAsqalānī, Aḥmad ibn ʻAlī; Abdul Hai; Sprenger, Aloys; Wajīh, Muhammad.. Kitab al-isabah fi tamyiz al-sahabah.. A biographical dictionary of persons who knew Mohammad.. https://catalog.hathitrust.org/Record/100162111.