Alaba Jonathan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Alaba Jonathan tí wọ́n bí ní ọjọ́ kínní, oṣù kẹfà ọdún 1992, jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ní ìlú Calabar, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà


iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alaba Jonathan bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ bọ́ùlọ̀lù gbígbá lábẹ́ ẹ̀ka ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ agbábọ́ọ̀lù Navy Angels. Lẹ́yìn tí ó kùnà láti pegedé sínú ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù aagbà ikọ̀ Navy Angels ni ó gvéra lọ sí inú ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Pelican Star ní ọdún 2010 níbi tí ó After she failed to qualify for the senior team of the Navy Angels, she moved to the Pelican Stars in spring 2010 lábẹ́ ìkọwọ́bọ̀wé àdéhùn .[1]


Ipa rẹ̀ nínú ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Jonathan jẹ́ ìkan lára ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù obìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó sì ti gbà bọ́ọ̀lù lẹ́ẹ̀kan rí fún ikọ̀ náà lẹ́ẹ̀kan rí. Ó ti ṣojú orílẹ̀-èdè rẹ̀ nínú ìdíje 2011 FIFA èyí tí ó wáyé ní orílẹ̀-èdè Germany gẹ́gẹ́ bí aṣọ́lé [2] Ṣáájú èyí ni ó ti kópa nínú ìdíje U-20 World Cup tí ó wáyé ní ọdún 2010 nínú ikọ̀ ọ̀jẹ́wẹ́wẹ́ U-20 ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Unknown (2 August 2013). "Futball Galore Media: Pelican Stars upset form books to qualify at the expense of Delta Queens". 
  2. Nordwest-Zeitung (17 June 2011). "Der WM-Kader von Nigeria". www.nwzonline.de. Archived from the original on 1 June 2019. Retrieved 1 June 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "U.S. U-20 WNT Ready To Take On Nigeria In Quarterfinals of 2010 FIFA U-20 Women's World Cup". Archived from the original on 24 May 2013. Retrieved 5 February 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)