Alexa Clay

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Alexa Clay ní World Affairs Council, San Francisco, ní ọdún 2015

Alexa Clay (bíi í Ọjọ́ ọ̀kànlélógún Oṣù kẹta Ọdún 1984 ní Cambridge, Massachusetts) jẹ́ akọ̀wé, sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ àti asèwadi ní ìlànà Okùn òwò. Ó kọ̀wé tí àkólé rẹ̀ n jẹ́ "Misfit Economy".[1][2][3][4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]