Jump to content

Ali Hassan al-Majid

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fáìlì:Ali hassan al-majid.jpg
Ali Hassan al-Majid
Igbejo Ali Hassan Al-Majid ni ilu Baghdad, Iraq (Dec. 18, 2004)

Ali Hassan al-Majid ti won maa n pe ni Chemical Ali ti o je ara ile ti o je ara ile Sadam Hussein ni won ti dajo iku fun ipa ti o ko nitori ipolongo ti o se tako awon Kurds ni 1988.