Jump to content

Alpha Blondy

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Alpha Blondy
Alpha Blondy at Solidays Festival, (Longchamp Racecourse), France, 2008
Alpha Blondy at Solidays Festival, (Longchamp Racecourse), France, 2008
Background information
Orúkọ àbísọSeydou Koné
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kínní 1953 (1953-01-01) (ọmọ ọdún 71)
Dimbokro, Côte d'Ivoire
Irú orinReggae
Occupation(s)Singer/Songwriter
Years active1981–present
WebsiteAlphaBlondy.info alphablondyjahgloryfoundation.org

Alpha Blondy (ojoibi January 1, 1953)[1] je olorin reggae to gbajumo kakiri aye. Alpha Blondy je bibiso bi Seydou Koné ni Dimbokro, Côte d'Ivoire (Ivory Coast). O unkorin ni ede abinibi re Dioula, ni Faranse ati ni Geesi, ati ni ekookan ni ede Larubawa tabi Heberu.[2]




  1. "De Dimbokro à Monrovia". Alphablondy.info. Retrieved 2012-04-03. 
  2. Emmanuel K. Akyeampong; Henry Louis Gates. "Blondy, Alpha". Oxford Reference. Retrieved 15 October 2013.