Amarachi Nwosu
Amarachi Nwosu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 29 September 1994 Washington, D.C., U.S | (ọmọ ọdún 30)
Orílẹ̀-èdè | Nigerian-American |
Ẹ̀kọ́ | Temple University |
Iṣẹ́ | Photographer, film maker |
Works | Black In Tokyo |
Website | amarachinwosu.com |
Amarachi Nwosu (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù Kẹ̀sán ọdún 1994) jẹ́ ayàwòrán, eléré àti akọ̀wé.[1][2] Ó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Òun ni oludasile Melanie Unscripted.[3][4] Eré ìtàn, Black in Tokyo tí ó ṣe tí farahàn ni International Centre of Photography ni ọdún 2017 ni ìlú New York , ó sì tí farahàn ni Ultra Super New Gallery ni ìlú Harajaku.[5][6][7]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn òbí Amarachi jẹ́ ọmọ íbò.[8] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Temple University ni ilẹ̀ Philadelphia.
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2019, Malala Yousafzai tí ó gbà ẹ̀bùn Nobel laureate youngest winner péè Nwosu láti ya àwọn àwòrán ní ìrìnàjò rẹ sì Tokyo.[9][10]Òun ni ó ya àwòrán fún àwọn ẹ̀yán gbajúmọ̀ bii Náómì Campbell nígbà tí ó wà sì ìlú Èkó ni Nàìjíríà [11][12] àti Ebonee Davis.[13] Ó sì ti ṣe adarí fún àwọn ère kékeré fún àwọn ilé iṣẹ́ bíi Nike ni Nàìjíríà.[14] Ó ti si ṣé pelu àwọn olórin bíi Mr Eazi, Yxng Bane, Nonso Amadi, Odunsi The Engine, Santi, Kwesi Arthur àti Tóbi Lou.[15][16] Ó si ṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi ayàwòrán fún Childish Gambino ni ọdún 2018.[17][18] Òun ni ayàwòrán fún ètò The Fader tí wọn ṣe ni orílẹ̀ èdè Japan.[19] Ni ọdún 2017, òun àti Stella McCartney jọ ní àríyànjiyàn.[20][20][21][22][23][24][25][26][27][28][29]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Nast, Condé. "Meet the Nigerian-American Photographer Tackling Fashion’s Complicated Relationship With Race". Vogue (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-08.
- ↑ "Amarachi Nwosu". OKAYAFRICA's 100 WOMEN (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-03-11. Retrieved 2019-08-08.
- ↑ "9-to-5: A Jet-Setting Documentarian Shares Her Tokyo Shopping Tips and the Secrets Behind Her Style". Vogue (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ Johnmarlon (2018-03-04). "Global Voices - Black In Tokyo: a Documentary About Life in Japan". Global Voices (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "I, Tokyo: Amarachi Nwosu". Time Out Tokyo (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-08.
- ↑ Jamison, Shantell E. (2017-12-08). "Filmmaker Seeks to Use Movies to Impact Cultural Representation". EBONY (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-08.
- ↑ "Filmmaker Amarachi Nwosu explores beauty and being black in Tokyo". Mic (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-08.
- ↑ "'Black in Tokyo' Explores Life as a Black Person Living in Japan". HYPEBAE. Archived from the original on 2020-11-25. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ Murakami, Sakura (2019-03-23). "At Tokyo summit, Malala Yousafzai urges world leaders to expand educational opportunities for women" (in en-US). The Japan Times Online. ISSN 0447-5763. https://www.japantimes.co.jp/news/2019/03/23/national/tokyo-summit-malala-yousafzai-urges-world-leaders-expand-educational-opportunities-women/.
- ↑ "Pioneering sushi chef Yuki Chizui is cutting away at Japan’s patriarchy, one sashimi at a time — Assembly | Malala Fund". Assembly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "Naomi Campbell and Imaan Hammam Take on Arise Fashion Week in Lagos". Vogue Arabia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-09. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "Amarachi Nwosu speaks on Nigeria's creative renaissance and using visual storytelling to create diverse narratives". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-25. Archived from the original on 2019-08-12. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "Ebonee Davis on Reclaiming Her African Identity and Seeing Ghana for the First Time". www.yahoo.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "This Nike Short Highlights the Power of Women Soccer Players In Nigeria". OkayAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-31. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "Kwesi Arthur, Ghana's King of the Youth, Wants to Take African Hip-Hop Global". OkayAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-14. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "Yxng Bane Has No Other Competition But Himself". OkayAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-01-11. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "Meet Ibra Ake, the Nigerian-American who produced Childish Gambino's "This is America"". Africans in America (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-12. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "You Heard It Here First: Top 5 Illest Hip-Hop Tours of 2018". BET.com. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "Watch Black in Tokyo, a short documentary about living in Japan as a black person". The FADER (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ 20.0 20.1 "Designer Stella McCartney Is Being Accused Of Cultural Appropriation". Essence (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "People Are NOT Happy With Stella McCartney's Show Of African Prints". HuffPost UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-10-05. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "Stella McCartney stole our look | IOL". www.iol.co.za (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "Stella McCartney accused of "fashion colonialism" after showing African-inspired prints". Topics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ Naidoo, Charmain (2018-11-30). "Africa: Old Traditions, New Labels". allAfrica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ Bauck, Whitney. "Stella McCartney Is Under Fire for Using Ankara Prints". Fashionista (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "raceAhead: New Research From Accenture For A More Equitable Workplace". Fortune (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.
- ↑ "Folks Are Mad At Stella McCartney For Ripping Off Designs That 'African Aunties' Have Been Wearing For Years". OkayAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-10-03. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ Animashaun, Damilola (2017-10-03). "Stella McCartney Has Pissed Africans Off (Again) With Their New Collection". Konbini Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-08-12. Retrieved 2019-08-12.
- ↑ sourcestaff (2017-10-05). "Stella McCartney Sparks Outrage With African Inspired Runway Looks". The Source (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-12.