Jump to content

Amazulu (orin)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
"Amazulu"
Fáìlì:Amanda Black Amazulu Single.jpg
Single by Amanda Black
from the album Amazulu
ReleasedOṣù Keje 1, 2016 (2016-07-01)
Recorded2016
Genre
LengthÀdàkọ:Duration
LabelAmbitiouz Entertainment
Songwriter(s)
Producer(s)
  • Lunatik
  • Christer
  • Vuyo Manyike
Amanda Black singles chronology
"Amazulu"
(2016)
"Separate"
(2016)

Amazulu jẹ́ àwo-orin àkọ́kọ́ ti olórin ilè South Africa, iyẹ̀n Amanda Black, tí ó jáde ní ọjọ́ kìíní oṣù keje ọdún 2016. Orin náà jẹ́ èyí tó mú Amanda Black bọ́ sí gbagede, nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn ló gbọ́ orin náà lásìkò tí ó jáde, ìye ìgbà tí àwọn ènìyàn gbọ́ orin náà jẹ́ ìgbà 53,000.

Wọ́n yan "Amazulu" fún àmì-ẹ̀yẹ Record of the Year ní South African Music Awards ẹlẹ́ẹ̀kẹtàlélógún irú ẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ Song of the Year ní Metro FM Awards.

Ọdún Ayẹyẹ ìgbàmì ẹ̀yẹ Àpèjúwe àmì-ẹ̀yẹ Èsì Ìtọ́ka
2017 Metro FM Music Awards Song of the Year Wọ́n pèé [1]
South African Music Awards Record of the Year Wọ́n pèé [2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Reporter, Citizen. "Amanda Black gets her first award and Twitter goes crazy". citizen.co.za. Retrieved 15 September 2017. 
  2. Reporter, Citizen. "Amanda Black talks her music journey & latest project". yomzansi.com. Retrieved 15 September 2017.