Aminatu Ibrahim
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | ọjọ kẹta osù kíní ọdún 1979 | ||
Playing position | Olùgbèjà | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Ghatel Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana | 8 | (0) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Aminatu Ibrahim tí a bí ní ọjọ kẹta osù kíní ọdún 1979 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Ghana tí òkè-òkun tí ó ń seré gẹ́gẹ́ bí olùgbèjà . Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin orílẹ̀-ède Ghana . Ó wà lára àwọn tí ó kópa ní bi FIFA Women's World Cup ti ọdún 2003 àti FIFA World Cup Women ti ọdún 2007. Lórí ìpele ẹgbẹ́, ó ṣeré fún Ghatel Ladies ní Ghana. [1]