Aminu Shariff
Ìrísí
Aminu Shariff | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kejì 1977 Galadanci, Kano, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Political Science |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Bayero University, Kano, Kano, Nigeria |
Iṣẹ́ | Filmmaker, story writer, director, TV Producer / Presenter[1] |
Ìgbà iṣẹ́ | 1996–present |
Notable credit(s) | Ukuba |
Awards | See below |
Aminu Aliyu Shariff tí a tún mọ̀ sí Aminu Momoh ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù Kejì ọdún 1977 l, jẹ́ adarí eré, ònkọ̀tàn, olùgbéré-jáde, ati oníṣẹ́ orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán, olóòtú ìwé ìròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Aminu Shariff's filmography
Ọdún | Àkòrí | Ipa tí ó kó | Genre | Production Company |
---|---|---|---|---|
2009 | Duniyar Sama | Actor | Drama | Movies World |
2010 | Guguwa | Actor | Drama | Movies World |
2010 | Tuwon Tulu | Actor | Drama | |
2010 | Tuwon Kasa | Actor | Drama | |
2011 | Kishiya ko 'Yar Uwa | Actor | Drama | |
2012 | Abu Naka | Actor | Drama | |
2012 | Ukuba | Actor | Drama | Movies World |
2013 | Kauna | Actor | Drama | |
2013 | A Cuci Maza | Actor | Drama | AlRahus Film Production |
2015 | Ana Wata Ga Wata | Actor | Drama | G. G. Production |
2015 | Gidan Farko | Actor | Drama | I. A. I. Entertainment |
2015 | Kayar Ruwa | Actor | Drama | |
2017 | Rumana | Actor | Drama | Hikima Multimedia kano |
Awards
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]List of awards received by Aminu Aliyu Shariff.
Year | Award | Category | Film | Result |
---|---|---|---|---|
2001 | Arewa Film Award[3] | Best Actor | Ukuba | Gbàá |
2005 | Gamji Awards | Best Actor of Year | Kauna | Gbàá |
2009 | Afro-Hollywood Award | Best Actor (Hausa Category) | Duniyar Sama | Gbàá |
2010 | Kano State Censorship Award | Best Actor | Makamashi | Gbàá |
2013 | City People Entertainment Awards | Best Actor | Kannywood Personality | Gbàá |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Aminu Shariff [HausaFilms.TV - Kannywood, Fina-finai, Hausa Movies, TV and Celebrities]".
- ↑ Muryar Arewa. "Aminu Aliyu - Muryar Arewa". Aminu Aliyu. Archived from the original on 23 August 2017. Retrieved 22 Aug 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Actors are understandably snobbish, says Aminu Momo". NigeriaFilms.com. Retrieved 18 May 2020.