Amy Adams

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Amy Adams
A photograph of Amy Adams attending the UK premiere of 'Nocturnal Animals' at the BFI London Film Festival in 2016
Adams ní ọdún 2016
Ọjọ́ìbíAmy Lou Adams
Oṣù Kẹjọ 20, 1974 (1974-08-20) (ọmọ ọdún 49)
Aviano, Italy
Orílẹ̀-èdèAmerican
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1994 – present
WorksFull list
Olólùfẹ́
Darren Le Gallo (m. 2015)
Àwọn ọmọ1
AwardsFull list

Amy Lou Adams (tí a bí ní ọjọ́ ogún oṣù kẹjọ ọdún 1974) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún apepe àti àwàdà nínú àwọn eré tí ó ma ń ṣe, ó wà lára àwọn òṣèrébìnrin tí wọ́n ń san owó fún jùlọ ní àgbáyé. Ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ, àmì-ẹ̀yẹ bi Golden Globe Awards méjì, wọ́n sì yán ní emefà mọ́ ara àwọn tí ó tó sí àmì ẹyẹ Academy Awards, ní emeje mọ́ ara àwọn tí ó tó sí British Academy Film Awards, àti ní emejì mọ́ ara àwọn tí ó tó sí Primetime Emmy Awards.

Adams bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi oníjó ní gbọ̀ngán oníjó láàrin ọdún 1994 sí 1998, ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré nígbà àkọ́kọ́ nínú eré Drop Dead Gorgeous (1999). Láti ìgbà náà, ó ti ṣeré nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré bi "mean girl", Catch Me If You Can (2002), Junebug (2005) - èyí tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Award fún.

Àwọn eré míràn tí ó ti farahàn ni Enchanted (2007), Doubt (2008), The Fighter (2010), The Master (2012), American Hustle (2013), Big Eyes (2014), Arrival (2016), Sharp Objects (2018), Vice (2018). Láàrin ọdún 2017,ó kó ipa Lios Lane nínú àwọn eré DC extended universe.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]