Jump to content

Anígunmẹ́ta

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Anígunmẹ́ta
A triangle
Edges and vertices3
Schläfli symbol{3}

Anigunmeta (triangle) je okan ninu ipilese irisi aniwonile: anigunpupo (polygon) pelu elenusonso (vertex) meta ati egbe meta ti won apa ila (line segment) gbooro. Irisi yi lo mu eka imo isiro ti a mo si Iwon anigunmeta (trigonometry) wa. Eyi fihan wa bi o se se pataki to.

Orisirisi awon anigunmeta

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A le se eka anigunmeta gege bi ibu awon egbe won se to:

Equilateral Triangle Isosceles triangle Scalene triangle
OníbùúkaánnàOníbùúméjìOníbùúmẹ́ta

A tun le se eka awon anigunmeta gege bi itobisi awon igun inu won se to:

Right triangle Obtuse triangle Acute triangle
OnígunrégéOnígunfẹ̀nfẹ̀Onígunsonso