Jump to content

Anígunpúpọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Awon orisirisi anigunpupo

Anígunpúpọ̀ ninu Jeometri je irisi aworan pepe ti o je pipade pipade pelu ila tabi ona ayipo, to ni itelentele tolopin awon ajapo ila gboro (eyun, pelu closed polygonal chain). Awon ajapo ila wonyi je pipe ni egbe tabi eti, be sini ojuami ti awon egbe mejeji ti pade ni an pe ni sonso tabi koro anigunpupo na. Inu re ni an pe ni ara.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]