Ana Joaquina dos Santos e Silva
Ana Joaquina dos Santos e Silva (1788–1859) jẹ óniṣowo oko ẹru ti ilẹ Euro-Afrika, ayanilowo, ati agbẹ ti ilẹ Angola. Arabinrin naa jẹ óniṣowo oko ẹru to tobi julọ ni Angola nibi ti o tin ṣè oko owo pẹlu brazil ni ọdun 1830s to si na owo fun inawo ti Joaquim Rodrigues Graça[1][2][3].
Igbèsi Àye Ana
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ana Joaquina dos Santos e Silva jẹ ọmọ ẹgbẹ ti class ti ilẹ Afro-Portuguese to ni ipo àṣiwaju si owo ṣiṣe agbegbe ti Portuguese Luanda nibi ti ara Europe alawọ funfun wọn ju ẹgbẹrun kan lọ. Arabinrin naa jẹ óniṣowo oko ẹru larin ilẹ Angola ati Afin ti Brazil ni ọdun 1830s-1840s[4]. Owo ẹku ṣise ni wọn fagile ni ọdun 1836 ṣugbọn iṣẹ naa tẹsiwaju nibi ti awujọ ti fi aye gba[5].
Ana dos Santos e Silva ni óriṣiriṣi oko fun sugar, cofee ati ile alaja mẹta ni Luanda[6] to pada wa di oun a pewo. Nigbati Brazil fagile oko owo ẹru ni 1850, owo naa kuna lati ṣiṣẹ eyi lo mu ki ana di oṣiṣe ile ifowopamọ, olowo oko owo ati iṣẹ owo irin ati awọn amofin[7][8].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ana Joaquina dos Santos e Silva (1789-1859) - Biografias de Mulheres Africanas". Biografias de Mulheres Africanas (in Èdè Pọtogí). 2020-12-13. Retrieved 2023-08-26.
- ↑ Pearce, Justin (2015-06-27). "Angolan ‘justice’ in a Portuguese slave house". Africa Is a Country. Retrieved 2023-08-26.
- ↑ Pacheco*, Carlos (1999-11-24). "A barbárie instalou-se em Angola". PÚBLICO (in Èdè Pọtogí). Retrieved 2023-08-26.
- ↑ "Slave Registers". Slave Registers. 2021-10-23. Retrieved 2023-08-26.
- ↑ Candido, Mariana P. (2018-09-26), Women in Angola, Oxford University Press, doi:10.1093/acrefore/9780190277734.013.569
- ↑ "Palácio Dona Ana Joaquina". Medicare Club (in Èdè Pọtogí). Retrieved 2023-08-26.
- ↑ "Enslaved: Peoples of the Historical Slave Trade". Enslaved.org. Retrieved 2023-08-26.
- ↑ Wheeler, Douglas L. (1996). "Angolan Woman of Means: D. Ana Joaquina dos Santos e Silva, Mid-Nineteenth Century Luso-African Merchant-Capitalist of Luanda". Santa Barbara Portuguese Studies 3: 284–297. https://www.africabib.org/rec.php?RID=A00000743. Retrieved 2023-08-26.