Jump to content

Anastasia Rodionova

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Anastasia Rodionova jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù Tennis tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù karùn ùn ọdún 1982, Ó jẹ́ ọmọ ará ilù Russia tí a bí sí orílẹ̀ èdè Australia.

Rodionova ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì ẹyẹ ní oríṣiríṣi àwọn ìdíje lágbàáyé bí i WTA Tour ati ITF Circuit.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]