Andrés de Santa Cruz
Appearance
Andrés de Santa Cruz je Aare ile Bòlífíà elekeje ni odun 1827. Ojo ibi ni ojo karun, osu kejila, odun 1792 (5th Dec, 1792) ni Huarina, Bolifia. O si ipo padap ni ojo keedogbon, osu kesan, odun 1865 (25th September, 1865) ni Beauviour, Manche France. E ni ti o je are Bolifia leyin re ni Manuel Salanzar y Banquijano. Awon obi re ni Jose de Santa Cruz y Villavcen ati arabirin Juana Basilla Calahumana.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |