Angelica Nwandu
Ìrísí
Angelica Nwandu | |
---|---|
Nwandu in 2020 | |
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kàrún 1990 Los Angeles, California |
Iṣẹ́ | Online Black celebrity gossip |
Ìgbà iṣẹ́ | 2014-present |
Gbajúmọ̀ fún | Founder, the Shade Room |
Angelica Nwandu (tí wọ́n bí ní May 10, 1990)[1][2] ni olùdásílẹ̀ the Shade Room (TSR), èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayélujára tó níṣe pẹ̀lú ṣíṣe òfófó àwọn gbajúmọ̀. Iye àwọn ènìyàn tó ń wo ètò yìí ń lọ bí i 20 million.[3][4] Ní ọdún 2016,The New York Times to the Shade Room sábẹ́ àwọn ètò tó gbajúmọl jù lọ ní orí ẹ̀rọ-ayélujára.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Abumere, Princess (May 10, 2017). "5 things you should know about the Shade Room founder". pulse.ng. Retrieved June 4, 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Today is my bday". www.instagram.com. Retrieved 2023-07-22.
- ↑ "Live Session With Angelica Nwandu CEO and Founder of The Shade Room". The Hype Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-16.
- ↑ Davis, Allison P. (2019-10-21). "How I Get It Done: Angelica Nwandu, Founder and CEO of The Shade Room". The Cut (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-22.
- ↑ Wortham, Jenna (April 14, 2015). "Instagram's TMZ". The New York Times.