Aniebiet Inyang Ntui

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Her Excellency

Professor Aniebiet Inyang Ntui
Official portrait of Aniebiet Inyang Ntui as University Librarian of the University of Calabar, Nigeria
Official portrait, 2022
European Green Deal
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
27 December 2022
ÀàrẹUrsula von der Leyen
AsíwájúOffice Established
University of Calabar Library
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
24 February 2022
ÀàrẹFlorence Banku Obi
Vice-Chancellor
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Alma materUniversity of Cross River State, Uyo (B.S.)
University of Ibadan, Nigeria (Master of Library and Information Science
Known forClimate and Biodiversity Advocacy, Literacy Advocacy, and Library Development
Signature
WebsiteWebsite

Ọjọgbọn Aniebiet Inyang Ntui jẹ afọrọwèrọ ati ònimọ ayika to ti ṣoju fun EU ti óju ọjọ Europe Pact lati ọdun 2022, óṣu December. Arabinrin naa ṣè alakoso awọn panel ni òniruru apejọ ti United Nations ni ọdun 2022 to waye ni Montreal, Canada,[1], Summit ti Bali G20 ọdun 2022 ni ilu Indonesia[2][3], apejọ ayipada òju ọjọ ti United Nations ni ọdun 2022 to waye ni Sharm el-Sheikh, Egypt, Summit lori òmi ilẹ ti United Nations to waye ni ólu ilu UNESCO, Paris, [4], Òju ọjọ 2023 Stockholm ati Economic Forum agbaye to waye ni Davos, Switzerland.

Ẹkọ Aniebiet[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aniebiet gba ami oye ti ólóyinbọ pe ni Bachelor's Degree lori imọ Botany lati ile iwe giga ti ipinlẹ Cross River[5], Arabinrin naa gba Diploma lori iṣẹ Kọmputa ati lilo rẹ ni ile iwe giga ti Ìbadan ati ami oye ti masters lori ẹkọ ni ilè iwè giga ti Calabar[6].Arabinrin naa tun gba ami oye ti Masters ni imọ ti yara ikawé, Archival ati iroyin lati ilé iwé giga ti Ìbadan, ami oye ti Ph.D lori yara ikawé ati iroyin lati ilè iwé giga ti Uyo[7].

Ìṣẹ Aniebiet[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aniebiet ti ṣè iwadi to damọran lori ilókuló ayika, awọn iwadi yi "Ariwó pipa ninu ayika ilè iwè giga" ti a fi afiti rẹ si ilè iwè giga ti Calabar, Calabar, órilẹ ede Naijiria" ni a ti kọ si Journal ti awujọ ayika ilẹ Naijiria ni ọdun 2004. Awọn iwadi yii to jẹ̀ koko iwadi ariwo pipa ni órilẹ ede Naijiria[8][9].

Ni óṣu December, ọdun 2022 Aniebiet ni a fi jẹ àṣoju ti EU European pact ti óju ọjọ. Awọn àṣoju EU maa gbe ófin ati ìṣẹ óju ọjọ larugẹ ni ayika ati agbègbè wọn[10][11].

Ni óṣu June, Ọdun 2023, Ọjọgbọn Aniebiet ṣè ipade pẹlu ààrẹ Volodymyr Zelenskyy ti ilu Ukraine lati sọrọ nipa ipa ti wiwo Dam ti Kakhovka dasi ayika pẹlu awọn eniyan jakan jakun ati ólóṣèlu[12][13].

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "UNICAL Prof In Montreal For Biodiversity Talks At COP 15". CalabarGist. 7 December 2022. Archived from the original on 10 January 2023. https://web.archive.org/web/20230110062202/https://calabargist.com/2022/12/07/unical-prof-in-montreal-for-biodiversity-talks-at-cop-15/. 
  2. "G20: Prof. Aniebiet Inyang of UNICAL in Indonesia for Climate Advocacy". Converseer. 14 November 2022. Archived from the original on 10 January 2023. https://web.archive.org/web/20230110092802/https://converseer.com/g20-prof-aniebiet-inyang-of-unical-in-indonesia-for-climate-advocacy/. 
  3. "UNICAL Prof In Indonesia For Climate Advocacy-G20". CalabarGist. 15 November 2022. Archived from the original on 10 January 2023. https://web.archive.org/web/20230110062159/https://calabargist.com/2022/11/15/unical-prof-in-indonesia-for-climate-advocacy-g20/. 
  4. "UNICAL Prof. to lead UN Summit in Paris". CalabarGist. 25 November 2022. Archived from the original on 10 January 2023. https://web.archive.org/web/20230110062207/https://calabargist.com/2022/11/25/unical-prof-to-lead-un-summit-in-paris/. 
  5. "Aniebiet Inyang Ntui". Geek Feminism Wiki. 2023-08-30. Retrieved 2023-09-09. 
  6. "Europeana PRO". Europeana PRO. Retrieved 2023-09-09. 
  7. "Aniebiet NTUI". ResearchGate. Retrieved 2023-09-09. 
  8. Ntui, Aniebiet Inyang; Onuu, Michael Ugwu. "Environmental Noise Pollution in Nigerian Universities: A Case Study of the University of Calabar, Calabar, Nigeria". Zenodo (Zenodo). doi:10.5281/ZENODO.5451542. https://zenodo.org/record/5451542. Retrieved 2023-09-09. 
  9. Ntui, Aniebiet Inyang. "Noise Sources and Levels at the University of Calabar Library, Calabar, Nigeria". Zenodo (Zenodo). doi:10.5281/ZENODO.5453890. https://zenodo.org/record/5453890. Retrieved 2023-09-09. 
  10. "EU Appoints UNICAL Prof as Ambassador". CALABARGIST. 2022-12-27. Archived from the original on 2023-10-08. Retrieved 2023-09-09. 
  11. "EU Appoints UNICAL Prof As Ambassador ▷ Waploaded". Read Forum Updates in September 2023 ▷ Waploaded. 2023-09-09. Retrieved 2023-09-09. 
  12. "UNICAL Prof Meets Ukrainian President". CALABARGIST. 2023-06-13. Archived from the original on 2023-10-08. Retrieved 2023-09-09. 
  13. "Volodymyr Zelenskyy held a video call with representatives of the global environmental protection community in Kryvyi Rih and invited them to join the international working group on countering Russia's environmental crimes". Official website of the President of Ukraine. 2023-09-08. Retrieved 2023-09-09.