Jump to content

Anita Alaire Afoke Asuoha

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Real Warri Pikin
Real Warri Pikin in an all-white Photoshoot
Ọjọ́ìbíAnita Alaire Afoke Asuoha
29 Oṣù Kẹ̀wá 1990 (1990-10-29) (ọmọ ọdún 34)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaBenson Idahosa University
Iṣẹ́
  • comedienne
  • actress
  • Actor
  • Filmaker
  • dancer
  • MC
Ìgbà iṣẹ́2008-present
Gbajúmọ̀ fúnStand up comedy, Skits, Humanitarian
Notable work(Schoool of Thought, Real Warri pikin Unfiltered, Real Warri pikin one million challenge)
Olólùfẹ́
Victor Ikechukwu Asuoha (m. 2013)
Àwọn ọmọ3
Websitehttps://realwarripikin.com

Anita Alaire Afoke Asuoha jẹ́ apanilẹ́ẹ̀rín Alámì-ẹ̀yẹ ètò Stand up, òṣèré, olóòtú ètò ìgbáfẹ́ lórí ẹ̀rọ ayélujára àti atọ́nisọ́nà lórí ọ̀rọ̀ ayé àti ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn, tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ jẹ́ Real Warri Pikin.

Ìgbésí ayé rẹ̀.

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Anita Asuoha tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1990, ó sì dàgbà ní ìlú Warri ní ìpínlẹ̀ Delta, Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Bàba rẹ̀ jẹ́ Ọmọ Ijaw láti ìjọba ìbílẹ̀ Burutu ní ìpínlẹ̀ Delta nígbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Urhobo. Ó jẹ́ ọmọ kẹta nínú ọmọ mẹ́fà.[1] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú Political science ní Fásitì Benson Idahosa ìlú Benin ní ọdún 2012. Ó fẹ́ ọ̀gbẹ́ni Victor Ikechukwu Asuoha ní ọdún 2013, wọ́n sì ní ọmọ mẹ́ta.[2][3][4][5]

Àwọn ìtọ́kasí.

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "How Anita Alaire Afoke Asuoha (realwarripikin) Became Warri's Biggest Female Export". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-12. Retrieved 2020-05-19. 
  2. "God bless the day your mum brought you to me". Legit Ng. Taiwo Owolawi. Retrieved 26 June 2021. 
  3. Ayomide, Damilola (2021-04-27). "Comedienne Real Warri Pikin Celebrates Wedding Anniversary With Husband". Information Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-10. 
  4. "Why I show off my family online –Real Warri Pikin". Punch Nigeria. Blessing Enenaite. Retrieved 6 November 2021. 
  5. "People accuse me of controlling my husband — Warri Pikin". Punch Nigeria. Oghenovo Egodo-Michael. Retrieved 19 November 2022.