Ann Chiejine
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 2 Oṣù Kejì 1974 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Playing position | Goalkeeper | ||
National team | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1991– | Nigeria women's national football team | 14 | |
† Appearances (Goals). |
Ann Chiejine jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini ọjọ keji, óṣu February ni ọdun 1974. Agbabọọlu naa jẹ goalkeeper fun team bọọlu apapọ awọn obinrin ilẹ naigiria[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ann kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 1991 ati olympic ti ọdun 2000[4].
- Elere naa yege ninu ere idije awọ̀n obinrin ilẹ afirica to waye ni ọdun 2016 gẹgẹbi oluranlọwọ coach[5].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.eurosport.com/football/ann-chiejine_prs414554/person.shtml
- ↑ https://fbref.com/en/players/ddcaf386/Ann-Chiejine
- ↑ https://gh.soccerway.com/players/ann-chiejine/291452/
- ↑ https://www.brila.net/chiamaka-nnadozie-is-the-one-most-reliable-super-falcons-goalie-since-ann-chiejine/#more
- ↑ https://bhmng.com/ann-chiejine-nigerias-safe-hands-ageing-like-fine-wine/