Anne Landsman

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Anne Landsman
Ọjọ́ ìbíWorcester, South Africa
Iṣẹ́Novelist
ÈdèEnglish
Ọmọ orílẹ̀-èdèSouth African
SpouseJames Wagman
Website
annelandsman.com

Anne Landsman (Ti a bi ni ọjọ́ kerinla osu kerin odun 1959) jẹ́ òǹkọ̀wé. Wọ́n bíi ni Worcester, South Africa, ó jẹ́ ọmọ Dọ́kítà , ó sì jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́-gboye ni University of Cape Town ati Columbia University. O sise oluko títì di ọdún 2001, O tun tesiwaju ninu ise Olùkọ́ ní ile-eko The New School university ni New York, níbití ó ń gbé pẹ̀lu ọkọ rẹ̀, James Wagman tí ó sise olùyàwòrán ilé,[1] àti àwọn ọmọ rẹ̀.[2]


Òun ni òǹkọ̀we àwọn ìwe wonyi ''The Devil's Chimney àti The Rowing Lesson. Ìwe àkọ́kọ́ rẹ̀ to súyọ lára ọ̀kan nínu àwọn ìtàn kúkurú tí ó ma ń tẹ̀ jáde sóri American Poetry Review; èkejì si farajọ ìtan-ìgbésí-ayé-ara-ẹni, tí ó ń sọ ìtan obìrin Jewish South African kan.[3]

Àwọn ìwe rẹ̀ wà nínu àtẹ̀jáde ní orílẹ̀-èdè United Kingdom, Germany, South Africa, the Netherlands, Norway and Denmark, àti ní U.S pẹ̀lú. Ó tun ṣe àfikùn àròkọ sí Ìwé àkójọpọ̀ ''Touch'', ''An Uncertain Inheritance'' àti ''The Honeymoon’s Over'' ó sì tun kọ̀we fún oríṣiríṣi òpó ìtẹ̀jáde bíi ''The Washington Post'', ''The American Poetry Review'', The Believer', ''The Guardian'' àti The Telegraph (UK). Ó tún kọ́ ni bí a tií n kọ̀wé ní Columbia University, Brooklyn College àti The New School for Social Research. Landsman wà lára ẹgbẹ́ ị̀gbị̀mọ̀ The Writers' Room ní New York City.

Novels[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awards[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Home". 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named bundu
  3. exhibit-E.com. "Anne Landsman - Biography". 
  4. "Bundublog.com". bundureviews.bundublog.com. Retrieved 2018-01-08. 

Àdàkọ:Authority control

Àdàkọ:SouthAfrica-writer-stub