Jump to content

Annona squamosa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán Annona squamosa lórí igi

Annona squamosa jẹ́ igi kékeré tàbi igi kúkurú[1] láti ìdílé Annonaceae tó ń so èso tó ṣe é jẹ, tí wọ́n ń pè ní sugar apples tàbí sweetsops.[2] Ó máa ń gba ìwọ̀n ojú ọjọ́ tó lọlẹ̀ díẹ̀ bí i ti Annona reticulata àti Annona cherimola (tí èso rẹ̀ sì ń jẹ́ orúkọ kan náà) tó sì máa ń mu rọrùn fún àwọn ẹ̀ka yòókù láti hù.[3] Annona squamosa jẹ́igi kékeré,[4] tó ga tó ìwọ̀n 3 to 8 metres (10 to 26 feet) [1][4] èyí tó jọ ti soursop (Annona muricata).[5] Ó jẹ́ ìbílẹ̀ sí tropical climateAmerica àti West Indies, àti àwọn tó ń ṣe ìdókòwò ní Spain sí Asia.[6]

Flower
Seedling
Branches

Èṣo A. squamosa (sugar-apple) ní adùn aláwọ̀ funfun, ó sì gbajúmọ̀ ní àwọn ọjà ńlá.

A. squamosa leaves

Ẹ̀ka rẹ̀ ní àwọ pálí pẹ̀lú egbò igi lára rẹ̀; twig rẹ̀ máa ń yí àwọ̀ padà pẹ̀lú àmì tó tò tò tó.

Sugar-apple ní energy, ó sì jẹ́ orísun vitamin C àti manganese, ó sì tún jẹ́ orísun thiamine àti vitamin B6, ó sì tún máa ń pèsẹ̀ vitamin B2, B3 B5, B9, iron, magnesium, phosphorus àti potassium ní ìwọ̀n tó tọ́.[7]

Michał Boym's drawing of, probably, the sugar-apple, in his Flora Sinensis (1655)

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "Compilation: Annona squamosa". Global Plants. JSTOR. Retrieved 2019-09-05. 
  2. (in en-US) The Complete Guide to Edible Wild Plants. United States Department of the Army. New York: Skyhorse Publishing. 2009. pp. 100. ISBN 978-1-60239-692-0. OCLC 277203364. https://www.worldcat.org/oclc/277203364. 
  3. Morton, Julia (1987). "Sugar Apple Annona squamosa". Fruits of warm climates. Department of Horticulture & Landscape Architecture, Purdue University. p. 69. Archived from the original on 5 April 2008. Retrieved 2008-04-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. 4.0 4.1 Kral, Robert. "Annona squamosa Linnaeus, Sp. Pl. 1: 537. 1753". In Flora of North America Editorial Committee. Flora of North America North of Mexico. 3. http://beta.floranorthamerica.org/Annona_squamosa. Retrieved 2019-09-05. 
  5. "Annona squamosa". Pacific Island Ecosystems at Risk (PIER). 2008-01-05. Archived from the original on 12 May 2008. Retrieved 2008-04-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Morton, Julia (1987). "Annona squamosa". Fruits of warm climates. p. 69. Retrieved 6 March 2013. 
  7. "Benefits of Custard apple". 22 December 2014. https://www.youtube.com/watch?v=0QgdQYKGIpM.