Anthony Daniels
Anthony Daniels | |
---|---|
Daniels ní ọdún 2011 | |
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kejì 1946 Salisbury, Wiltshire, England |
Iṣẹ́ | Actor, mime artist |
Ìgbà iṣẹ́ | 1974–present |
Gbajúmọ̀ fún | C-3PO in Star Wars (1977–present) |
Olólùfẹ́ | Christine Savage (m. 1999) |
Website | anthonydaniels.com |
Anthony Daniels ( /ˈæntəni/ AN-tə-nee;[1] tí a bí ní ọjọ́ kanlélógún oṣù kejì ọdún 1946)[2] jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain, tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ fún ipa gẹ́gẹ́ bi C-3PO nínú eré Star Wars mẹ́wàá.[lower-alpha 1]
Daniels ni ó fọ ohùn fún Legolas nínú eré Ralph Bakshi bẹ̀bí tí wọ́n ṣe fún The Lord of the Rings (1978). Ó ti farahàn nínú àwọn Britain kọ̀kan. Daniels jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní Entertainment Technology Center ti Yunifásitì Carnegie Mellon.[3]
Ìpìlẹ̀ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Daniels ní ìlú Salisbury, Wiltshire, England.[4] Ó kàwé ní ilé ìwé Giggleswick School ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin fún ọdún méjì ní Yunifásitì, ṣùgbọ́n ó kúrò láti kópa nínú amateur dramatics lẹ́yìn tí ó padà lọ Rose Bruford College. Lẹ́yìn ìgbà tí ó kàwé gboyẹ̀ ní Burford College ní ọdún 1974, Daniels ṣiṣẹ́ ní on BBC Radio àti fún gbọ̀ngán erẹ́ National Theatre ti Great Britain ní The Young Vic. Níbi tí ó ti ń sisẹ́ ní gbọ̀ngán náà ni wọ́n ti pé láti pàdé George Lucas, ẹni tí ó ń wa àwọn ènìyàn láti ṣeré nínú Star Wars.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Jimmy Kimmel Live interview with J.J. Abrams and cast of The Rise of Skywalker (Jimmy Kimmel Live official YouTube channel)
- ↑ "Biography". Anthony Daniels official website. Archived from the original on 11 May 2019. Retrieved 3 December 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Faculty / Staff | Entertainment Technology Center". www.etc.cmu.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-03-19.
- ↑ Lubow, Arthur. "The Forces Behind Jedi: Making Movie History Took Lucas & Co. to the Outer Limits", People, vol. 20, no. 6, 8 August 1983.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found