Anti-LKM antibody
Ìrísí
Wọ́n maa ń rí Anti-Liver Kidney Microsomal Antibodies (Anti-LKM antibody) nínú omi inú ẹ̀jẹ̀ àwọn aláìsàn tí wọ́n ní oríṣiríṣi àrùn èyí tí kò léwu àti èyí tó léwu tí ẹ̀dọ̀. Àwọn adojú ìjà kọ àrùn yí maa ń dojú kọ àwọn cytochrome P450 tí wọ́n lòdì sí ara. Oríṣi mẹ́ta Anti-LKM ni wọ́n ti ṣe ìwádí tó péye lórí rẹ̀.
Adojú ìjà kọ àrùn ti Microsol | Ohun tí ó lòdì sí ara |
Àrùn |
---|---|---|
Anti-LKM 1 | Cytochrome P450 2D6 | Autoimmune hepatitis type II àti Chronic Hepatitis C(10%) |
Anti-LKM 2 | Cytochrome P450 2C9 | Drug-induced hepatitis (Tienilic acid induced) |
Anti-LKM 3 | Cytochrome P450 1A2 | Chronic active hepatitis pẹ̀lú Autoimmune Polyendocrine Syndrome type 1;[1] Hepatitis D |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Gebre-Medhin G et al., FEBS Letters 1997