Jump to content

Anti-glomerular basement membrane antibody

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Anti-glomerular basement membrane antibody (anti-GBM Ab) jẹ́ adojú ko ìjà àrùn tí a ń rí ní Goodpasture's syndrome ṣùgbọ́n tí wọn kò rí ní microscopic polyangiitis.

Àwọn ibì kan gbà wípé " àrùn anti-GBM" àti "àrùn Goodpasture" jọ ara wọn látàrí ẹ̀yà, tí ó jẹ́ kí wọ́n maa lo "Goodpasture syndrome" fún àgbékalẹ̀ ìlera.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ped/117 at eMedicine

Àwọn ìjápọ̀ látìta

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]