Anti-histone antibodies
Ìrísí
Anti-histone antibodies jẹ́ àwọn èròjà ìdáàbòbò ara tí ara má ń ṣètò rẹ̀ tí wọ́n sì maa ń ri ní ìdá àádọ́ta (50%) sí ìdá àádọ́rin (70%) àwọn aláìsàn tí wọ́n ní àrùn systemic lupus erythematosus (SLE) àti àwọn tí ó ju 95% àwọn aláìsàn tí wọ́n ní àrùn drug-induced lupus erythematosus.[1]
ELISA tí wọ́n fi ń ṣe ìwádí anti-histone antibodies maa sọọ́ di mímọ̀ wípé ó wà lára tí ó bá rí ju 25 units/ml anti-histone antibodies nínú ẹ̀jẹ̀.[2]
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Table 5-9 in: Mitchell, Richard Sheppard; Kumar, Vinay; Abbas, Abul K.; Fausto, Nelson (2007). Robbins Basic Pathology. Philadelphia: Saunders. ISBN 1-4160-2973-7.
- ↑ chronolab.com > Autoantibodies associated with rheumatic diseases > Reference ranges Archived 2013-07-30 at the Wayback Machine. Retrieved on April 29, 2010