Anti-nRNP

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Anti-nRNP jẹ́ irú adojú ìjà kọ àrùn.[1][2]

Wọ́n jẹ́ àwọn adojú ìjà kọ àrùn tí ara maa ń dédé ṣètò rẹ̀ lati dojú ìjà kọ àwọn ribonucleoproteins.[3]

Ẹ̀yà  Anti-nRNP jẹ́ adojú ìjà kọ snRNP70 (wọ́n ń pèé ní anti-snRNP70). Adojú ìjà kọ Anti-snRNP70 lè lọ sókè ní àrùn  mixed connective tissue.[4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]