Jump to content

Ántígúà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Antigua)
Antigua
Native name: Wadadli
Map of Antigua
Jẹ́ọ́gráfì
IbùdóCaribbean Sea
Àwọn ojú-afọ̀nàhàn17°5′N 61°48′W / 17.083°N 61.800°W / 17.083; -61.800Coordinates: 17°5′N 61°48′W / 17.083°N 61.800°W / 17.083; -61.800
Àgbájọ erékùṣùLeeward Islands
Ààlà281 km2 (108.5 sq mi)
Etíodò87 km (54.1 mi)
Ibí tógajùlọ402 m (1,319 ft)
Orí ilẹ̀ tógajùlọ̀Mount Obama
Orílẹ̀-èdè
Antigua and Barbuda
Ìlú tótóbijùlọSt. John's (pop. 31,000)
Demographics
Ìkún85,632 (as of July 2009 est.)
Ìsúnmọ́ra ìkún245.55 /km2 (635.97 /sq mi)
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn91% Black or Mulatto, 4.4% Other Mixed Race, 1.7% White, 2.9% Other
Turner Beach in Antigua

Ántígúà (pípè /ænˈtiːɡwə/ an-TEE-gwə tabi, labele, an-TEE-gə) je erekusu kan ni West Indies, larin awon Erekusu Leeward ni agbegbe Karibeani, ohun ni erekusu gbangba orile Ántígúà àti Bàrbúdà. Antigua tumosi "atijo" ni ede Spani o si je sisoloruko latowo Christopher Columbus fun aworan kan ni Seville Cathedral, eyun Santa Maria de la Antigua—Maria Mimo ara Atijo. O tun je mimo bi Wadadli, lati inu ede awon awon Amerindia ibe tele, o si tumo si "ti wa". Iyipo erekusu na je 87 km (54 mi) be sini aala re je 281 km2 (108 sq mi). Olugbe ibe je 69,000 ni Osu Keje 2006.[1] Ohun ni o tobijulo larin awon Erekusu Leeward, ati eyi to dagbasoke julo to si ni asiki julo nitori idara ise isabewosi, ifowopamo offshore, iwofa tete lori internet ati iwofa eko to ni ile eko iwosan meji.


  1. "Nation by Nation population estimate". Archived from the original on 2008-06-29. Retrieved 2010-08-23.