Ántígúà àti Bàrbúdà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Antigua and Barbuda)
Ántígúà àti Bàrbúdà Antigua and Barbuda | |
---|---|
Motto: Each Endeavouring, All Achieving | |
Orin ìyìn: Fair Antigua and Barbuda | |
![]() | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Saint John's |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Geesi |
Local language | Antiguan Creole |
Orúkọ aráàlú | Antiguan, Barbudan |
Ìjọba | Parliamentary democracy under a federal constitutional monarchy |
Elizabeth II | |
Rodney Williams | |
Gaston Browne | |
Igbominira latowo Ileoba Aparapo | |
• Ojoodun | 1 Osu Kokanala, 1981 |
Ìtóbi | |
• Total | 440 km2 (170 sq mi) (195th) |
• Omi (%) | negligible |
Alábùgbé | |
• 2009 estimate | 85,632 (191st) |
• Ìdìmọ́ra | 194/km2 (502.5/sq mi) (57) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $1.522 billion[1] |
• Per capita | $17,892[1] |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $1.178 billion[1] |
• Per capita | $13,851[1] |
HDI (2007) | ▲ 0.868 Error: Invalid HDI value · 47th |
Owóníná | East Caribbean dollar (XCD) |
Ibi àkókò | UTC-4 (AST) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left |
Àmì tẹlifóònù | +1-268 |
Internet TLD | .ag |
|
Ántígúà àti Bàrbúdà (pípè /ænˌtiːgwə æti bɑːɹˈbjuːdə/ ( listen); Spani fun "atijo" ati "onirungbon") je is a twin-orile-ede erekusu-meji larin Omi-okun Karibeani ati Okun Atlantiki. O ni erekusu meji ninla ti awon eniyan ungbe be, Ántígúà ati Bàrbúdà, pelu awon erekusu kekeke melo kan (bi awon Erekusu Great Bird, Green, Guinea, Long, Maiden ati York).
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 "Antigua and Barbuda". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.