Jump to content

Apoti

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àpọ́tí jẹ́ ohun ìjókòó tí ó ní orí pẹrẹsẹ tí a fi igi tàbí pákó ṣe. Ẹnìkan ṣoṣo péré ni àpótí lè gbà lórí ìjókòó kan, bákan náà ni kò ní igun tí a lè gbé ọwọ́ lé lọ́tún tàbí lósì. Ó ma ń ní ẹsẹ̀ méjì, mẹ́ta tàbí mẹ́rin, èyí dá lórí agbègbè tí a bá ti ríi. A kò lè sọ wípé àga ni àpótí, nítorí àì ní apá tàbí igun tí a lè fí ọwọ́, tàbí fi ẹ̀yìn tì sí.

.[1] [2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Apoti stool". HOG Furniture. 2021-07-26. Archived from the original on 2021-07-26. Retrieved 2021-07-26. 
  2. "What does apoti mean in Yoruba?". WordHippo. 2009-02-19. Retrieved 2020-03-03.