Ariela Barer
Ariela Barer | |
---|---|
Barer in 2018 | |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kẹ̀wá 1998 |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2007–present |
Àwọn olùbátan | Libe Barer (sister) |
Ariela Barer tí wọ́n bí ní ọjọ́ oṣù Kẹrìnlá oṣù Kẹwàá ọdún 1998, jẹ́ òṣèrébìrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tí ó di ìlú-mòọ́ká fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré Hulu tí ó jẹ́ ìpele Runaways gẹ́gẹ́ bí Gert Yorkes
Ìgbà èwe rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ Jew[1] TheirẸ̀gbọ́n rẹ̀ Libe Barer náà jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé.
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ariela bẹ̀rẹ̀.ṣíṣe ní ìgba tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́ta, amọ́ tí ó mu iṣẹ́ náà ní ọ̀kúnkúndùn ní ìgbà tí ó di ọmọ ọdún Mẹ́sàn án. Ó ti kópa nínú àwọn eré oríṣiríṣi ati awọn àwo orin onírúurú bíi The Love-Inns.[2]Ó ti kópa gẹ́gẹ́ bí Gert Yorkes nínú eré Runaways, tí wọ́n kọ́kọ́ gbé jáde ní Hulu.[3] Ó tún kópa bí Carmen nínú eré One Day at a Time.
Ìgbé ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní inú oṣù Kọkànlá ọdún 2016, Barer fi léde wípé ènìyàn oníbálòpọ̀ akọ-sákọ ni òun ní orí ìkànnì Twitter rẹ̀. [4][5] and has given their pronouns as 'they/them' on their Instagram profile, indicating they are non-binary.[6]
Àwọn àṣàyàn eré.rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2009 | An American Girl: Chrissa Stands Strong | Sonali Matthews | Direct-to-video |
Stellina Blue | Kamand | ||
2011 | All Kids Count | Maria | |
2017 | A Place I'd Like To Be | Short film | |
2018 | Ladyworld | Olivia |
Eré.orí.ẹ̀rọ amóhù-máwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2007 | Yo Gabba Gabba! | Super Martian Robot Girl (voice) | Recurring |
2008 | ER | Jasmine Escalante | Episode: "Life After Death" |
90210 | Rana Shirazi | Episode: "Games People Play" | |
2009 | Valentine | Young Wendy | Episode: "She's Gone" |
Weeds | Scout | Episode: "Perro Insano" | |
2011 | Keenan's Crush | Samantha | 4 episodes |
2012 | New Girl | Young Cece | 2 episodes |
2013 | King John | Sofie | Television film |
2014 | Modern Family | Sophie | Episode: "And One to Grow On" |
I Didn't Do It | Megan | Episode: "Ball or Nothing" | |
Gortimer Gibbon's Life on Normal Street | Esther Pendragon | Episode: "Ranger and the Legend of Pendragon's Gavel" | |
2015 | Liv and Maddie | Shayna | Episode: "Muffler-A-Rooney" |
The Thundermans | Kylie | Episode: "Exit Stage Theft" | |
2016 | K.C. Undercover | Alexis McCreery | Episode: "Undercover Mother" |
2017 | One Day at a Time | Carmen | 4 episodes |
2017–2018 | Atypical | Bailey Bennett | 7 episodes |
2017–2019 | Runaways | Gertrude "Gert" Yorkes | Main cast |
2020 | Grey's Anatomy | Paula | Episode: "Life on Mars?" |
2021 | Rebel[7] |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "'One Day at a Time's Goth Carmen Is Now a Superhero on Marvel's Runaways". remezcla.com.
- ↑ "The Love-Inns". Bandcamp. Retrieved July 28, 2017.
- ↑ Strom, Marc (February 2, 2017). "Marvel's Runaways Finds Its Cast". Marvel.com. Archived from the original on February 3, 2017. Retrieved February 2, 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Mey (December 24, 2017). "Ariela Barer is Gay: "One Day at a Time" and "Runaways" Star Comes Out on Twitter, Happy Holigays Everybody". Autostraddle. Retrieved May 8, 2018.
- ↑ "Ariela Barer on Twitter". Twitter. Retrieved February 7, 2019.
- ↑ https://www.instagram.com/arielabarer/?hl=en
- ↑ "Rebel Drama From Grey's Boss, Starring Katey Sagal, Gets Series Order at ABC". TVLine.com. Retrieved September 18, 2020.
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pages with citations using unsupported parameters
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1998
- 21st-century American actresses
- 21st-century American singers
- 21st-century American women singers
- American child actresses
- American people of Mexican descent
- American people of Mexican-Jewish descent
- American television actresses
- Jewish American actresses
- Lesbian actresses
- LGBT Hispanic and Latino American people
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Place of birth missing (living people)
- LGBT Jews