Jump to content

Àròkọ Oníròyin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Aroko alariyanjiyan)

Àròkọ Oníròyìn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àròkọ Oníròyìn jẹ́ àròkọ tí a fi ń ròyìn ìṣẹ̀lẹ̀ kan tí ó sojú ẹni tàbí èyí tí wọ́n sọ fún ni, Ṣé Yorùbá bọ̀ wọ́n ni ohun tó ṣojú ẹni kì í sẹ̀yìn ẹni bẹ́ẹ̀ ni ìròyìn kò tó àfojúba, ẹni tí ó dé ibẹ̀ ló lè sọ.

Àpẹẹrẹ Àròkọ Oníròyìn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Ọdún iléyá tí ó wáyé ní ọdún yìí
  • Bí mo ṣe lo ìsinmi mi tí ó kọjá
  • Ọjà alẹ́ ní ìlú mi

Ètò lẹrù igi, ó ṣe pàtàkì nígbà tí a bá ń kọ àròkọ oníròyìn, a gbọ́dọ̀ ròyìn nǹkan náà tàbí ṣe àpejúwe ohun tí à ń ròyìn ní ọ̀nà tí ó jẹ́ pé ẹni tí kò rí ohun nǹkan náà yóò fi fi ojú ya àwòrán ohun tí à n sọ nípa rẹ̀

A kò gbọ̀dọ̀ ṣe àfikún tàbí àyọ̀kù ìṣẹ̀lẹ̀ tí a n ṣe ìròyìn

rẹ̀ .[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]