Asghar Hussain Deobandi
Àdàkọ:Use Indian English Àdàkọ:Infobox religious biography Asghar Hussain Deobandi (ti atun lè pé ní Mian Sayyid Asghar Hussain) (16 October 1877 — 8 January 1945) jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ Mùsùlùmí Indian Sunni ó pẹ̀lú àwọn olùdásílẹ̀ Madrasatul Islah.
Wọ́n bí i ní ọjọ́ kẹrìndínlógún, oṣù kẹwàá, ọdún 1877 sí ìdílé Deoband, ó jẹ́ olóòótọ́ ènìyàn sí Abdul Qadir Jeelani, Asghar Hussain Deobandi jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ gboyè ni Darul Uloom Deoband, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ pẹ̀lú Mahmud Hasan Deobandi, Azizur Rahman Usmani àti Hafiz Muhammad Ahmad. Hussain Jẹ́ ọmọlẹ́yìn fún Imdadullah Muhajir Makki nínú Chishti Sufi order. Ó kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ́ńsì nínú ẹ̀sìn Atala Masjid, Jaunpur àti ní ibi tí ó tí kẹ́kọ̀ọ́ gboyè, Darul Uloom Deoband. Ó pẹ̀lú àwọn tó ṣe àfikún sí ìwé osooṣù tí àwọn Darul Uloom Deoband máa ń tẹ̀ jáde, èyí tí à ń pè ní Al-Qasim'. Hussain jẹ́ ìpè Ọlọ́run ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù kìíní, ọdún 1945 (January 8,1945) ní Surat. Wọ́n si ín sí Rander. Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ni wọ̀nyí Manazir Ahsan Gilani àti Muhammad Shafi Deobandi.
Ìdílé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn baba ńlá Mian Asghar Hussain wá sí ìlú India láti ìlú Baghdad wọ́n wá sí ọ̀nà ìsàlẹ̀ láti Abdul Qadir Jeelani. [1] ní ìgbà ayé àwọn Shah Jahan, Sayyid Ghulam Rasool ti lọ sí ìlú India òun àti àwọn ẹbí rẹ̀. [1] wọ́n yọ̀ǹda Imamat àti khitabat fún un ní ibi Shahi Masjid tí Deoband. Ó ní ọmọkùnrin méjì, Ghulam Nabi àti Ghulam Ali. Àwọn ọkùnrin méjèèjì fẹ́ ọmọ obìnrin ti Shah Ameerullah. [1]
Sayyid Ghulam Ali ní ọmọ obìnrin mẹ́ta àti ọkùnrin méjì. Èyí tí ó dàgbà jù tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Alam Meer ẹni tí ó jẹ́ bàbabàbá Mian Asghar Hussain. Alam Meer fẹ́ Azeemun Nisa, ọmọbìnrin tì Shah Hafeezullah. Wọ́n ní ọmọ obìnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Wajeeh-un-Nisa àti ọmọkùnrin tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Muhammad Hasan, ó jé bàbá fún Mian Asghar Hussain.[2] Muhammad Hasan fẹ́ ìyàwó méjì, àkókò o fe Maryam-un-Nisa, tí ó bí ọmọkùnrin kan fún un tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Sayyid Khursheed, àti ọmọbìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Masum-un-Nisa. Lẹ́yìn ikú After Maryam-un-Nisa's, Muhammad Hasan fẹ́ àbúrò rè tó ń jẹ́ Naseeb-un-Nisa;[lower-alpha 1] won ni omokunrin kàn, Asghar Hussain.[3]
Ibi àti Ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ibi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àbí Mian Asghar Hussain ni ọjọ́ kẹrìn-dín-lógún oṣù Kẹ̀wáa, ọdún 1877 (16 October, 1877) ní ìlú Deoband sí ìdílé Sayyid Muhammad Hasan àti Naseebun Nisa bint Sayyid Mansub Ali.[3]
Orúko àti ìdílé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orúkọ Mùsùlùmí rẹ̀ ni ism (given name) Asghar Hussain. Tire nasab (patronymic) is: Sayyid Asghar Hussain ibn Sayyid Shah Muhammad Hasan ibn Sayyid Shah Alam Meer ibn Sayyid Ghulam Ali ibn Sayyid Ghulam Rasool Baghdadi ibn Sayyid Shah Faqeerullah Baghdadi ibn Sayyid A’zam Saani ibn Sayyid Nazar Muhammad ibn Sayyid Sultan Muhammad ibn Sayyid A’zam Muhammad ibn Sayyid Abu Muhammad ibn Sayyid Qutbuddin ibn Sayyid Baha’uddeen ibn Sayyid Jamalauddin ibn Sayyid Qutbuddin ibn Sayyid Dawud ibn Muhi’uddin Abu Abdullah ibn Sayyid Abu Saleh Nasr ibn Sayyid Abdur Razzaq ibn Abdul Qadir Jilani.[4]
Ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nígbà tí ó pé ọmọ ọdún mẹ́jọ, ó ń kẹ́kọ̀ọ́ pẹ̀lú Muhammad Abdullah, alias Miyanji Munne Shah[lower-alpha 2] ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ Quran láti ọwọ́ bàbá rẹ̀, ó tẹ̀ síwájú láti kọ́ nípa Persia lọ́wọ́ bàbá rẹ̀. Wọ́n padà gbà á wọlé sí Ìle ẹ̀kọ́ Darul Uloom Deoband. Ó tẹ̀ síwájú pẹ̀lú kíláàsì Persia ó kọ́ Persian lọ́wọ́ Muhammad Yaseen, bàbá Muhammad Shafi Deobandi. Ó kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìsirò ní Manzoor Ahmad. Ó yege nínú ẹ̀kọ́ persiani pẹ̀lú ipò kìíní, ó sì gba ẹ̀bùn Muwatta Imam Malik gẹ́gẹ́ bíi ẹ̀bùn ìdánilọ́lá. Bí Asghar Hussain ṣe pé ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún sí méjìdínlógún tí ó dé iyàrá ìkàwé arabic ní Darul Uloom Deoband, bàbá rẹ̀ jáde láyé ni ogúnjọ, oṣù Kẹ̀sán ọdún 1894. Ó dá ẹnu dúró nínú èkó rè fún bí ọdún kan, ó sì tẹ̀síwájú láti kó àwọn ọmọ lẹ́kọ̀ọ́ ní madrasa àwọn baba-ńlá rẹ̀.
Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ àwọn Mahmud Hasan Deobandi, Asghar Hussain wọ ilé ẹ̀kọ́ Darul Uloom Deoband lẹ́ẹ̀kan si ní ọjọ́ kì-ín-ní, oṣù kẹrin, ọdún 1896. Ó tún tẹ̀síwájú nínú ètò ìkẹ́kọ̀ọ́ Arabic. Ó kọ́ nípa Sahih al-Bukhari, Sahih Muslim, Jami` at-Tirmidhi àti Sunan Abu Dawood pẹ̀lú Mahmud Hasan Deobandi. Àwọn olùkọ́ rẹ̀ tó ní ni Azizur Rahman Usmani àti Ghulam Rasool Baghwi. Ó kọ́ ẹ̀kọ́ gboyè ní 1320 AH Ó sì gba àmì ìkẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ọwọ́ Mahmud Hasan Deobandi àti Hafiz Muhammad Ahmad.[5]
Ó gba àṣẹ ọmọ lẹ́yìn ti Imdadullah Muhajir Makki ninu eka Chishti ti Tasawwuf.[7][8]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lẹ́yìn ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Darul Uloom Deoband, o ṣe iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ ní Darul Uloom fún bí ọdún kan. Àwọn olùkọ́ rẹ̀ Mahmud Hasan Deobandi àti Hafiz Muhammad Ahmad rán an lọ sí madrassa ti Atala Masjid, Jaunpur fún ipò olùkọ́ àgbà ó sì ṣiṣẹ́ fún ọdún méje. Ní àwọn àkókò yìí ní ọdún 1327 AH, ó fi òkúta ilé Madrasatul Islah lé ilẹ̀ ní Sarai Meer, Azamgarh ní 1908.[9] a pè é sí Darul Uloom Deoband a sì fún un ní ipò alátúnṣe pẹ̀lú àwọn tó ń ṣe àtúnṣe sí journal Al-Qasim ti Darul Uloom, tí alátúnṣe náà sì jẹ́ Maulana Habeebur Rahman. A fún un ní ipò olùkọ́ ti Sunan Abu Dawud ní Darul Uloom Deoband ó tún kò àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní ìwé tafsir àti fiqh like Jalalayn àti Durr-e-Mukhtar.[8][5] His notable students include Muhammad Shafi Deobandi,[10] Manazir Ahsan Gilani.[11] and Mufti Naseem Ahmad Fareedi. Ó tún madrasa àwọn baba-ńlá rẹ̀ ṣe tí a ti parí láti ìgbà ikú bàbá rẹ̀. madrasa padà wá lábẹ́ àkóso ọmọkùnrin rẹ̀ Sayyid Bilal Hussain Mian (d. 9 February 1990) orúkọ rẹ̀ láwàní pé ni Madrassa Asgharia Qadeem tí orúkọ ìtàn rẹ̀ ń jẹ́ Darul Musafireen, Madrasa Taleemul Quran.[8]
Iṣẹ́ Mọ̀ọ́komọ̀ọ́kà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Asghar Hussain tí kọ bí ìwé ọgbọ̀n ní èdè Urdu, including:[12]
- Fatawa Muhammadi
- al-Jawab al-Matin bi-Ahadith Sayyid al-Mursaleen
- Miras al-Muslimin
- Mufeed-ul-Wariseen
- Hayat-e-Khizer
- al-Qawl al-Matin fi al-Iqamati wa at-Taziin
- Gulzar-e-Sunnat
- Molvi Ma'anwi (biography of Rumi)
- Hayat-e-Shaykhul Hind (biography of Mahmud Hasan Deobandi)
- Kulliyat Shaykhul Hind
ìgbéyàwó àti ìgbé ayé ẹbí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ìgbà ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní Darul Uloom Deoband, Hussain fẹ́ ọmọbìnrin ti Mushtaq Hussain. Wọ́n ní ọmọkùnrin méjì, tí ń ṣe Sayyid Akhtar Hussain àti Mian Bilal Hussain, àti ọmọbìnrin kan, Fehmeeda. [13] Fehmeeda kú lẹ́yìn ọdún mẹ́jọ tí ó ṣe ìgbéyàwó, ọmọ rẹ ọkùnrin sì gbẹ̀yìn rẹ̀ Syed Farhat Hussain tí òní àjòṣepọ̀ pẹ̀lú Hamdard Dawakhana ní Karachi. [13] ọmọkùnrin Hussain's tí ń jẹ́ Sayyid Akhtar Hussain jẹ́ olùkọ́ hadith ni Darul Uloom Deoband, ó sì ni ọ́fíìsì seminari.[13] Hussain's àti àwọn ọmọkùnrin Sayyid Bilal Hussain ọmọkùnrin mẹ́ta tí ń ṣe, Sayyid Jameel Hussain, Sayyid Khaleel Hussain, and Sayyid Jaleel Hussain sì gbẹ̀yìn won; àti ọmọbìnrin méjì tí ń se, Sajida Khatun àti Aabida Khatun.[13]
Ikú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àìsàn ọkàn pa Mian Asghar Hussain ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù kìíní, ọdún 1945 (22 Muharram 1364 AH). wọ́n sin ín si Rander, Surat.[8][5]
See also
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Notes
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Maryam-un-Nisa ati Naseeb-un-Nisa je ọmọbìnrin tí Sayyid Mansab Ali
- ↑ Miyanji Munne Shah jẹ́ ẹ̀gbọ́n sí Azeemun Nisa, ìyàwó Syed Alam Meer,owasi odò àbúrò ìyá Asghar Hussain's baba Sayyid Muhammad Hasan àti Sayyid Muhammad Hasan jẹ́ ẹ̀gbọ́n rẹ̀. [5] Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ Muhammad Qasim Nanautawi, ò fi òkúta àkókò lè ilé fún ilé tuntun ti Darul Uloom Deoband. Sayyid Muhammad Abid wá kín in lẹ́yìn, Rasheed Ahmad Gangohi. Jẹ́ ẹni ìgbẹ̀yìn tí ó fi òkúta ikẹ tuntun silé pẹ̀lú wọn Muhammad Qasim Nanautawi.[6]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 Hussayn, Sayyid Jameel, Tadhkirah Hadhrat Miyan Saheb, pp. 32–33
- ↑ Hussayn, Sayyid Jameel, Tadhkirah Hadhrat Miyan Saheb, pp. 33–34
- ↑ 3.0 3.1 Hussayn, Sayyid Jameel, Tadhkirah Hadhrat Miyan Saheb, pp. 49–51
- ↑ Hussayn, Sayyid Jameel, Tadhkirah Hadhrat Miyan Saheb, pp. 191–194
- ↑ 5.0 5.1 5.2 5.3 Dr. Syed Jameel Hussain (in Urdu). Tazkirah Hazrat Miyan Saheb. Madrasa Islamia Asgharia, Deoband.
- ↑ Muhammad Miyan Deobandi. Ulama-e-Haq Ke Mujahidana Karname. 1. Faisal Publications, Deoband. p. 55.
- ↑ Abu Muhammad Maulana Sana'ullah Shujabadi (in Urdu). Ulama-e-Deoband Ke Aakhri Lamhaat (2015 ed.). Maktaba Rasheediya Saharanpur. p. 51.
- ↑ 8.0 8.1 8.2 8.3 Syed Mehboob Rizwi (in English). ìtàn awon Dar al-Ulum Deoband. 2 (1981 ed.). Dar al-Ulum Deoband: Idara-e-Ehtemam. p. 61,62,143.
- ↑ "Islamic Education in Modern India" (PDF). p. 76. Retrieved 25 March 2020.
- ↑ Justice Mufti Muhammad Taqi Usmani (in Urdu). Akabir-e-Deoband Kya Thy (May 1995 ed.). Zamzam Book Depot, Deoband. p. 54.
- ↑ Manazir Ahsan Gilani. "Profile of Maulana Manazir Ahsan Gilani by Syed Azhar Shah Qaiser" (in Urdu). Hazaar Saal Pehle (July 2004 ed.). Al-Ameen Kitabistaan, Deoband. p. 13.
- ↑ Hussayn, Sayyid Jameel, Tadhkirah Hadhrat Miyan Saheb, pp. 198–207
- ↑ 13.0 13.1 13.2 13.3 Hussayn, Sayyid Jameel, Tadhkirah Hadhrat Miyan Saheb, pp. 169–171, 193–194
Ìgbésí ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Hussayn, Sayyid Jameel (in Urdu). Tadhkirah Hadhrat Miyan Saheb. Deoband: Madrasa Islamia Asgharia.