Asha Rashid

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Asha Rashid
Personal information
Playing positionIwájú
National team
Tanzania
† Appearances (Goals).

Asha Rashid jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Tanzania tí ó gbá ipò iwájú lórí pápá fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin fún orílẹ̀-èdè Tanzania.[1][2][3][4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Cecafa 2016: Tanzania edge out Rwanda". Goal. Retrieved 9 October 2021. 
  2. "Asha Rashid set to join Top Club in Tukey's Women's league". TanzaniaSports. Retrieved 9 October 2021. 
  3. "Tanzania inflict more pain on Crested Cranes". 25 November 2019. Retrieved 9 October 2021. 
  4. "Cecafa: Rashid nets brace as Tanzania edge Rwanda in five goal thriller". Jesports. 12 September 2016. Archived from the original on 9 October 2021. Retrieved 9 October 2021.