Ashanti to Zulu
Ìrísí
Fáìlì:CM ashanti zulu.jpg | |
Olùkọ̀wé | Margaret Musgrove |
---|---|
Illustrator | Leo àti Diane Dillon |
Country | Amẹ́ríkà |
Genre | Ìwé àwòrán fún àwọn ọmọdé |
Publisher | Dial Books |
Publication date | 1976 |
ISBN | Àdàkọ:ISBNT |
OCLC | 2726240 |
960 | |
LC Class | GN645 .M87 |
Ashanti to Zulu: African Traditions jẹ́ ìwé àwòrán fún àwọn ọmọdé kan tí Margaret Musgrove ko tí Leo àti Diane Dillon sì ya àwórán rẹ̀ ní ọdún 1976. Òun ni ìwé àkọ́kọ́ tí Musgrove kọ, ṣùgbọ́n àwọn Dillons jẹ́ ògbóntarìgì ayaworán, ìwé yìí mú kí wọ́n gba àmì-ẹ̀yẹ Caldecott Medals lé kejì.[1] (Ìwé àkọ́kọ́ tí wọ́n fún wọn ní àmì ẹyẹ yìí fún ni Why Mosquitoes Buzz in People's Ears: A West African Tale.[1])
Àwòrán mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n àwọn ọmọ Áfríkà ni ó wà nínú ìwé yìí, pẹ̀lú àwọn àkọ́lẹ̀ díẹ̀ tí ó ń ṣàlàyé àṣà àti ìṣe wọn.
Àwọn tó wà nínú ìwé náà ni:
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 American Library Association: Caldecott Medal Winners, 1938 - Present. URL accessed 27 May 2009.