Ashraf Ghani

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ashraf Ghani
اشرف غني
Ghani in 2018
President of Afghanistan
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 September 2014
Vice PresidentAmrullah Saleh
Sarwar Danish
Abdul Rashid Dostum
AsíwájúHamid Karzai
Chancellor of Kabul University
In office
22 December 2004 – 21 December 2008
AsíwájúHabibullah Habib
Arọ́pòHamidullah Amin
Minister of Finance
In office
2 June 2002 – 14 December 2004
ÀàrẹHamid Karzai
AsíwájúHedayat Amin Arsala
Arọ́pòAnwar ul-Haq Ahady
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Ashraf Ghani Ahmadzai

19 Oṣù Kàrún 1949 (1949-05-19) (ọmọ ọdún 75)
Logar, Afghanistan
Ọmọorílẹ̀-èdèAfghan[1]
American (before 2009)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent
(Àwọn) olólùfẹ́Rula Ghani
ẸbíHashmat Ghani Ahmadzai (brother)
Àwọn ọmọMariam
Tariq
Alma materAmerican University of Beirut
Columbia University
Kabul University
Nickname(s)Baba

Ashraf Ghani (Pashto/Àdàkọ:Lang-prs; ọjọ́ìbí 19 May 1949) ni olóṣèlú ará Afghanístàn tó wà nípò gẹ́gẹ́ bíi Ààrẹ ilẹ̀ Afghanístàn lọ́wọ́lọ́wọ́. Wọ́n kọ́kọ́ dìbòyàn ní 20 September 2014, wọ́n sì tún tún-dìbòyàn ní 28 September 2019. Ghani jẹ́ onímọ̀ ìdá-ènìyàn, tẹ́lẹ̀ ó siṣẹ́ bíi Alákóso Ètò Ìṣúná àti bíi Kánsélọ̀ Yunifásítì Kabul.


Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named aspistrategist.org.au