Asif Ali Zardari

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Asif Ali Zardari
آصف علی زرداری
آصف علي زرداري
Ààrẹ ilẹ̀ Pakístàn
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
10 March 2024
Alákóso ÀgbàShehbaz Sharif
AsíwájúArif Alvi
In office
9 September 2008 – 9 September 2013
Alákóso ÀgbàYousaf Raza Gillani
Raja Pervaiz Ashraf
Mir Hazar Khan Khoso (Caretaker)
Nawaz Sharif
AsíwájúMuhammad Mian Soomro (Acting)
Arọ́pòMamnoon Hussain
Abáṣe-Alága Ẹgbẹ́ Àwọn Èníyàn Pakístàn
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
30 December 2007
Serving with Bilawal Zardari Bhutto
AsíwájúBenazir Bhutto
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Keje 1955 (1955-07-26) (ọmọ ọdún 68)
Karachi, Pakistan[1]
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeoples Party
(Àwọn) olólùfẹ́Benazir Bhutto (1987–2007)
Àwọn ọmọBilawal
Bakhtawar
Asifa
ResidenceIslamabad, Pakistan

Asif Ali Zardari (Urdu: آصف علی زرداری; Sindhi: آصف علي زرداري; ojoibi 26 July 1955) ni Aare ile Pakistan 11k lowolowo ati Abase-Alaga Egbe Awon Eniyan Pakistan (PPP). Zardari ni opó-kùnrin Benazir Bhutto, eni to je Alakoso Agba ile Pakistan ni emeji. Nigba ti iyawo re je didakupa ni Osu Kejila 2007, o di olori egbe PPP. Awon kan ti wi pe Zardari ni ikan larin awon olowojulo marun ni Pakistan pelu idiye iyi ohun ini to to US$1.8 billion (2005).[5][6]



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. [https://web.archive.org/web/20120620142443/http://www.presidentofpakistan.gov.pk/index.php Archived 2012-06-20 at the Wayback Machine.? lang=en&opc=2&sel=2
  2. "The Martyrdom of Benazir Bhutto". Huffingtonpost.com. 2008-01-03. Retrieved 2010-08-06. 
  3. Vali Nasr The Shia Revival: How Conflicts Within Islam Will Shape the Future (W. W. Norton, 2006), pp. 88-90 ISBN 0-393-32968-2
  4. Bokhari, Farhan (2010-11-29). "Pakistan-Saudi Relations Appear Strained in Leaked Cables". CBS News. Archived from the original on 2012-07-28. https://archive.is/SLO3. 
  5. Malik, Salik (2008-10-26). "President Asif Ali Zardari 2nd most Richest man of Pakistan | Pakistan Daily". Daily.pk. Archived from the original on 2012-01-13. Retrieved 2010-08-06. 
  6. Burns, John F. (1998-01-09). "HOUSE OF GRAFT - Tracing the Bhutto Millions - A special report. - Bhutto Clan Leaves Trail of Corruption - Special Report". Pakistan: NYTimes.com. http://www.nytimes.com/1998/01/09/world/house-graft-tracing-bhutto-millions-special-report-bhutto-clan-leaves-trail.html. Retrieved 2010-08-06.