Jump to content

Assétou Diakité

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Assétou Diakité
No. 32 – Stade Malien
PositionÀárín
LeagueMD1
Personal information
Bornọjọ́ kẹẹ̀dógún osù kejì Ọdún 1998
Bamako, Mali
NationalityMalian
Listed height1.93 m (6 ft 4 in)
Listed weight75 kg (165 lb)
Career information

Assétou Diakité tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún osù kejì Ọdún 1998 jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá fún Stade Malien àti ẹgbẹ́ orílẹ̀-ède Malian . [1]

Ó ṣe asojú Mali ní bi Afrobasket fún àwọn Obìrin ní Ọdún 2019 . [2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Assétou Diakité at FIBA